Anelloviridae jẹ́ ẹbí àwọn àkóràn kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn kan tí a ṣẹ̀ṣẹ̀ mọ́. Wọ́n kàwọ́n sí àkóràn kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn tí ó légungun tí ó sì ní ẹ̀wù ìdáàbòbò tí o gbó dáradára, tí ó rí róbótó, tí igun rẹ̀ jọ ara wọn, pẹ̀lú ogún igun tó jọrawọn. Àwọn ẹ̀yà wọ̀n yí jẹ́ àkóràn kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn ti torque teno  (ìdílé Alphatorquevirus).[1]

Anellovirus
Ìṣètò ẹ̀ràn
Group:
Group II (ssDNA)
Ìdílé:
Anelloviridae
Genera

Alphatorquevirus
Betatorquevirus
Gammatorquevirus
Deltatorquevirus
Epsilontorquevirus
Etatorquevirus
Iotatorquevirus
Thetatorquevirus
Zetatorquevirus

Iye jíìnì tó ní

àtúnṣe

Iye jíìnì ẹ̀ ko pín sí wẹ́wẹ́ tí ó sì ní molecule róbóto, pẹ̀lú apá DNA kan. Gbogbo iye jíìnì rè. jẹ́ bíi  3000 sí 4000 gígun ne nucleotide.[2]

Anellovirus jẹ́ àwọn ẹ̀yà tí ó wọ́pọ̀ tí ó sì pé oríṣiríṣi. Wọ́n maa ń fa àkóràn nlá tí a kò tíì mọ ìbáṣepọ̀ rẹ̀ pẹ̀lú àìsàn.[3] Ẹbí mẹta ni ó ní ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú àkóràn ènìya: kòkòrò àìlèfojúrí ti Torque teno (TTV), kòkòrò àìlèfojúrí pélébé ti Torque teno midi (TTMDV) àti kòkòrò àìlèfojúrí mini ti (TTMV).

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Torque Teno Virus (TTV) distribution in healthy Russian population". Virology Journal 6: 134. 2009. doi:10.1186/1743-422X-6-134. PMC 2745379. PMID 19735552. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=2745379. 
  2. ICTVdB Management (2006). 00.107.0.01.
  3. "Transfusion transmission of highly prevalent commensal human viruses". Transfusion 50 (11): 2474–2483. May 2010. doi:10.1111/j.1537-2995.2010.02699.x. PMID 20497515. 

Àwọn àjápọ̀ latì ìta

àtúnṣe