Betatorquevirus jẹ́ idile àwọn àkóràn kòkòrò àìlèfojúrí afàìsàn kan tí a ṣẹ̀ṣẹ̀ mọ́ ni ebi Anelloviridae, ní ẹgbẹ́ II in the Baltimore classification. Ó ṣàkójọpọ̀ ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn àkóràn kòkòrò àìlèfojúrí tí a mọ̀ tẹ́lè sí TLMV, TTV-like Minivirus tàbí àwọn kòkòrò àìlèfojúrí midi ti Torque teno pélébé

Betatorquevirus
Ìṣètò ẹ̀ràn
Group:
Group II (ssDNA)
Ìtò:
Unassigned
Ìdílé:
Ìbátan:
Betatorquevirus
Àwọn ẹ̀yà
  • kòkòrò àìlèfojúrí pélébé ti Torque teno

Àwọn tí ó wà ní ìdílé Betatorquevirus ni àwọn kòkòrò àìlèfojúrí pélébé ti Torque teno 1–9.

Lati àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ti parapneumonic empyema àwọn kòkòrò àìlèfojúrí pélébé ti Torque teno ti di fífàyọ.[1] Ìbáṣepọ̀ rẹ̀ nínú ìlera kó tíì yéwa.

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Galmès J, Li Y, Rajoharison A, Ren L, Dollet S, Richard N, Vernet G, Javouhey E, Wang J, Telles JN, Paranhos-Baccalà G (2012) Potential implication of new torque teno mini viruses in parapneumonic empyema in children.

Àwọn àjápọ̀ látìta

àtúnṣe