Ango Abdullahi je ọmọ orilẹ-ede Nàìjíríà omowe ati oloselu. O jẹ Igbakeji Yunifasiti ti Ahmadu Bello nígbà kàn ri ati pè o ti jẹ aṣoju ẹkun ìdìbò Iwọ-oorun Zaria tẹlẹ ni ipinlẹ Kaduna. [1] [2]

Ango Abdullahi
Ọjọ́ìbí13 December 1938
Old Giwa Village, Kaduna
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity of Ibadan, Ahmadu Bello University
Olólùfẹ́Senator Aisha Alhassan
Àwọn ọmọAngo Sadiq Abdullahi
AwardsCommander of the Order of the Niger (CON), Magajin Rafin Zazzau

Igbesi aye ara ẹni

àtúnṣe

Ango Abdullahi je Musulumi o si je bàbá Ango Sadiq Abdullahi omo ile aṣojú.[2]

Eto ẹ̀kọ́

àtúnṣe

O bẹrẹ eko alakọbẹrẹ ni Kali Elementary School ni ọdun 1944 kí ó tó dadasi ilé-ìwé Giwa Elementary School ni ọdun kan na. O lọ si ile-ẹkọ Barewa college laarin ọdun 1953 sì ọdun 1958, ó kàwé gboyè ni unifasiti Ibadan àti Ahmadu Bello University Zaria kí ó tó di adarí àgbá ni ile eko Ahmadu Bello Zaria.[3]

Awọn itọkasi

àtúnṣe