Àngúíllà

(Àtúnjúwe láti Anguilla)

Àwọn Akóìjánupọ̀: 18°13′14″N 63°4′7″W / 18.22056°N 63.06861°W / 18.22056; -63.06861 Anguilla Nínú ètò ìkànìyàn 1995, àwọn ènìyàn tó wa ní Anguilla jẹ́ ẹgbẹ̀rún méje àti ọgọ́rùn-ún (7,100). Èdè Gẹ̀ẹ́sì ni wọ́n ń sọ níbẹ̀. Púpọ̀ nínú àwọn ènìyàn ibẹ̀ ni wọ́n ń sọ èdè Kirió tí wọ́n gbé ka èdè Gẹ̀ẹ́sì (English based Creole). Kirió yìí ni ó wọ́pọ̀ jù ní Áńtílẹ́ẹ̀sì (Lesser Antilles)

Anguilla
Àsìá Àmì ọ̀pá àṣẹ
Motto"Strength and Endurance"
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèGod Save the Queen
National song: God Bless Anguilla 1
OlúìlúThe Valley
Èdè àlòṣiṣẹ́ English
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn  90.1% West African, 4.6% Multiracial, 3.7% European, 1.5% other[1]
Orúkọ aráàlú Ará Àngúíllà
Ìjọba British Overseas Territory
 -  Monarch HM Queen Elizabeth II
 -  Governor William Alistair Harrison
Ìdásílẹ̀
 -  UK overseas territory 1980 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 91 km2 (220th)
35 sq mi 
 -  Omi (%) negligible
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2006 13,600[2] (212th)
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 132/km2 (n/a)
342/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2004
 -  Iye lápapọ̀ $108.9 million 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $8,800 
Owóníná East Caribbean dollar (XCD)
Àkókò ilẹ̀àmùrè (UTC-4)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ left
Àmìọ̀rọ̀ Internet .ai
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù +1-264
1 "National Song of Anguilla". Official Website of the Government of Anguilla. Retrieved 12 October 2005. ItokasiÀtúnṣe

  1. Anguilla World Fact Book
  2. Country Profile: Anguilla, Travel & Living Abroad, Foreign & Commonwealth Office