Aniefiok Dennis
Aniefiok Dennis jẹ agbẹjọ́rò ati olóṣèlú Naijiria kan. O je omo egbe to n soju àgbègbè Etinan Sni ilé ìgbìmò aṣòfin kékeré ni ipinlẹ Akwa Ibom O jẹ ọmọ ẹgbẹ ti Peoples Democratic Party. [1] [2]
Aniefiok Dennis | |
---|---|
Member of Akwa Ibom State House of Assembly | |
In office June 2015 – June 2023 (re-run) | |
Constituency | Etinan |
Special Adviser on Legislative Matters to Godswill Akpabio | |
In office 2003–2007 | |
Senior Special Assistant on Legal Matters to Godswill Akpabio | |
In office 2013–2014 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Peoples Democratic Party |
Occupation | Politician, Lawyer |