Godswill Akpabio
Olóṣèlú Nàìjíríà
Godswill Akpabio jẹ́ agbẹjọ́rò àti olósèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Naijiria, ohùn ni Ààrẹ ilé ìgbìmò Asòfin lọ́wọ́lọ́wọ́,[1][2] òun sì ni Gómìnà Ipinle Akwa Ibom láti ọdún 2007 títí di ọdún 2015.[3]
Godswill Obot Akpabio | |
---|---|
Governor of Akwa Ibom State | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 29 May 2007 | |
Asíwájú | Obong Victor Attah |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 19 Oṣù Kejìlá 1962 Ukana, Ikot Ntuem, Akwa Ibom State, Nigeria |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Oyero, Kayode (13 June 2023). "UPDATED: Akpabio Sworn In As Senate President". Channels Television. Retrieved 13 June 2023.
- ↑ Obeme-Ndukwe, Ifunanya (13 June 2023). "Akpabio elected Senate President". Daily Post Nigeria. Retrieved 13 June 2023.
- ↑ "Enough is enough". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-07-30. Retrieved 2022-02-22.