Tina Turner
Tina Turner (tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ Anna Mae Bullock; tí wọ́n sì bí ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù November, ọdún 1939 - 2023) jẹ́ akọrin àti òṣèré ará Amerika tí iṣẹ́ rẹ̀ gbajúgbajà. Ó gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ, bẹ́ẹ̀ sì ni iṣẹ́ rẹ̀ nínú orin rock ti jẹ́ kí àwọn kan ó pè é ní "Queen of Rock 'n' Roll".[1][2][3] Turner bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ orin kíkọ pẹ̀lú ọkọ rẹ̀, ìyẹn Ike Turner, gẹ́gẹ́ bíi ọmọ ẹgbẹ́ olórin Ike & Tina Turner Reuve.[4] Àwọn ènìyàn sì tẹ́wọ́ gbà wọ́n látàrí àwọn orin wọn bíi "River Deep, Mountain High" àti "Proud Mary". Nínú ìtẹ̀jáde ìwé tó ti sọ ìtàn nípa ara rẹ̀, nínú Tina (1986), Turner ṣàfihàn àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ńlá tí ojú rẹ̀ rí látàri ìkọlù láti ọdọ ọkọ rẹ̀, ṣáájú ìpínyà wọn ní ọdún 1976 àti ìgbà tí wọ́n kọra wọn sílẹ̀ ní 1978. Lẹ́yìn ìṣẹ̀lẹ̀ yìí ló pòórá nínú iṣẹ́ orin kíkọ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún, ó wá ṣàtúnkọ́ iṣẹ́ rẹ̀, èyí tó ti ṣàgbéjáde orin àdákọ rẹ̀, tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ "Let's Stay Together", àti èyí tó gbé jáde ní ọdún 1984 tó pè ní Private Dancer.
Tina Turner | |
---|---|
Tina Turner performing in the GelreDome, 1985 | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Anna Mae Bullock |
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi | Tina Turner |
Ọjọ́ìbí | 26 Oṣù Kọkànlá 1939 Nutbush, Tennessee, U.S. |
Irú orin | Rock, pop-rock, pop, soul |
Occupation(s) | Singer, dancer, author, actress |
Instruments | Vocals |
Years active | 1958–2020 |
Labels | EMI, United Artists, Capitol, Parlophone, Virgin |
Associated acts | The Ike & Tina Turner Revue |
Iṣẹ́ rẹ̀ nínú orin kíkọ mu wọ inú eré ṣíṣe, èyí tó sì bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ẹ̀dá-ìtàn ńlá-ńlá bíi The Acid Queen nínú fíìmù Tommy tiọdún 1975, àti àfihàn rẹ̀ nínú Sgt. Pepper's Lonely Hearts Club Band. Ó ṣe ẹ̀dá-ìtàn kan láti ṣe ìdàkejì Mel Gibson bíi Aunty Entity nínú Mad Max Beyond Thunderdome inú èyí tó gba àmì-ẹ̀yẹ NAACP Image Award for Outstanding Actress in a Motion Picture. Ó tún farahàn nínú fíìmù ti ọdún 1993 kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Last Action Hero.
One of the world's most popular entertainers, Turner has been called the most successful female rock artist[5] and was named "one of the greatest singers of all time" by Rolling Stone.[6] Her combined album and single sales total approximately 180 million copies worldwide.[7][8] She has sold more concert tickets than any other solo music performer in history.[9][10] She is known for her energetic stage presence,[2] powerful vocals, career longevity,[9] and widespread appeal.[11] In 2008, Turner left semi-retirement to embark on her Tina!: 50th Anniversary Tour.[12][13] Turner's tour became one of the highest selling ticketed shows of 2008–2009.[8] Turner was born a Baptist, but converted to Buddhism and credits the spiritual chants with giving her the strength that she needed to get through the rough times.[14] Rolling Stone ranked her at 63 on their 100 greatest artists of all time and considers her the "Queen of Rock and Roll".[15]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Rafferty, Terrence (2008-07-27). "Tina Turner: Queen of Rock 'n' Roll". The New York Times. Retrieved 2008-10-27.
- ↑ 2.0 2.1 Wolman, Baron. "Gallery of The Popular Image". San Francisco Art Exchange. Retrieved 2008-10-27.
- ↑ "Tina Turner on Stage". San Francisco Art Exchange. Retrieved 2008-09-03.
- ↑ Bego, Mark (2005-09-23) [2003]. Tina Turner: Break Every Rule. Taylor Trade Publishing. ISBN 158979253X.
- ↑ "Biography on Tina Turner". Biography.com. A&E Television Networks. Retrieved 2008-09-03.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedrolling
- ↑ "Tina Turner heads for Brum city limits". Express & Star. 2008-09-23. Archived from the original on 2009-06-17. Retrieved 2008-10-27.
- ↑ 8.0 8.1 Terry, Al (2008-09-21). "Tina Turner Live Tickets – One Of The Biggest Selling Concert Tickets Ever". Pressemeldungen.at. Archived from the original on 2009-06-17. Retrieved 2008-10-27.
- ↑ 9.0 9.1 "Amway Global to be Presenting Sponsor of 'Tina Turner Live in Concert' 2008". Reuters.com. 2008-07-10. Retrieved 2008-10-31.
- ↑ Busnar, Gene (April 1987 2007) [1987]. The Picture Life of Tina Turner (Library Binding ed.). F. Watts Publishers. ISBN 0531102971.
- ↑ "Tina Turner 'One More Time: Live in Concert'". Tomfraley.com. 2008-09-18. Archived from the original on 2017-12-22. Retrieved 2008-10-31.
- ↑ Gundersen, Edna (2008-09-30). "Tina Turner is back by popular demand". USA Today. Retrieved 2008-10-27.
- ↑ "Tina Turner, 68, back by popular demand". Clarion Ledger. 2008-10-02. Retrieved 2008-10-27. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "CBS News". CBS News. 2002-09-21. Retrieved 2011-03-09.
- ↑ "100 Greatest Artists of All Time" Rolling Stone