Anna Paquin
Anna Paquin /ˈpækwɪn/ PAK-win tí wọ́n bí ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kéje, ọdún 1982) jẹ́ òṣèrébinrin orílẹ̀-èdè New Zealand to gba Ebun Akademi Obinrin Osere Keji Didarajulo.[1]
Anna Paquin | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Anna Hélène Paquin 24 Oṣù Keje 1982 Winnipeg, Manitoba, Canada |
Ọmọ orílẹ̀-èdè |
|
Ẹ̀kọ́ | Yunifásítì Kòlúmbíà |
Iṣẹ́ | Òṣèrébinrin |
Ìgbà iṣẹ́ | 1993–títí di asikò yi |
Olólùfẹ́ | Stephen Moyer (m. 2010) |
Àwọn ọmọ | 2 |
Ìgbà èwe àti bí ó ṣe kẹ́kọ̀ọ́
àtúnṣeWọ́n bí Anna Paquin sí Winnipeg, Manitoba, o jẹ́ ọmọ Mary Paquin (née Brophy) ati Brian Paquin.[2] Paquin lọ sí ile ẹ́kọ́ alakọbréẹ̀ Raphael House Rudolf Steiner School kí o tó tẹ̀sìwájú lo Hutt Intermediate School (1994-95), ti o si lo ile-iwe girama ti Wellington Girls' College, ó gba rẹ̀ ìwé-éri girama ni Windward School in ìlú Los Angeles.
Awọn Fíímù tí o tí Kópa
àtúnṣeỌdún | Àkọ́ọ́lé | Ipa | Akìyésìí |
---|---|---|---|
1993 | The Piano | Flora McGrath | |
1996 | Jane Eyre | Young Jane Eyre | |
Fly Away Home | Amy Alden | ||
1997 | Amistad | Queen Isabella II of Spain | |
1998 | Hurlyburly | Donna | |
Laputa: Castle in the Sky | Sheeta (voice) | English dub | |
1999 | A Walk on the Moon | Alison Kantrowitz | |
She's All That | Mackenzie Siler | ||
It's the Rage | Annabel Lee | ||
2000 | X-Men | Marie / Rogue | |
Almost Famous | Polexia Aphrodisia | ||
Finding Forrester | Claire Spence | ||
2001 | Buffalo Soldiers | Robyn Lee | |
2002 | Darkness | Regina | |
25th Hour | Mary D'Annunzio | ||
2003 | X2 | Marie / Rogue | |
2005 | Steamboy | James Ray Steam (voice) | English dub |
The Squid and the Whale | Lili | ||
2006 | X-Men: The Last Stand | Marie / Rogue[3] | |
2007 | Blue State | Chloe Hamon | Also executive producer |
Mosaic | Maggie (voice) | ||
Trick 'r Treat | Laurie | ||
2010 | The Romantics (film) | Lila Hayes | |
Open House | Jennie | ||
2011 | Scream 4 | Rachel | Cameo |
Margaret | Lisa Cohen | ||
The Carrier | Kim | Short film | |
2013 | Straight A's | Katherine | |
Free Ride | Christina | Also producer | |
2014 | X-Men: Days of Future Past | Marie / Rogue | Cameo; The Rogue Cut |
2015 | The Good Dinosaur | Ramsey (voice) | |
2018 | Furlough | Lily Benson | |
The Parting Glass | Colleen | Àtí gẹ́ẹ́gẹ bí olóòtú | |
Tell It to the Bees | Dr. Jean Markham | ||
2019 | The Irishman | Peggy Sheeran | |
2021 | American Underdog | Brenda Warner |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Sayre, Will (July 5, 2022). "Anna Paquin's 5 Best Performances, Ranked". MovieWeb. Retrieved August 27, 2022.
- ↑ "Anna Paquin. Biography, news, photos and videos". hellomagazine.com. January 1, 1970. Retrieved August 27, 2022.
- ↑ Maher, Dani (June 1, 2022). "Anna Paquin on Flack, True Spirit, & Her Love Of Powerful Female Roles". Harper's Bazaar Australia. Retrieved August 27, 2022.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |