Anne Baxter
Anne Baxter ni wọ́n bí ní ọjọ́ keje oṣù kaarun ọdún 1923 , tí o si dágbére fáye ni ọjọ́ kéjììlá, oṣù kéjììlá, ọdún 1985.[2] Ó jẹ́ òṣèrébinrin to gba Ebun Akademi ti Obinrin Osere Keji Didarajulo nígbà áye rẹ̀.
Anne Baxter | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Michigan City, Indiana, U.S. | Oṣù Kàrún 7, 1923
Aláìsí | December 12, 1985 New York City, U.S. | (ọmọ ọdún 62)
Resting place | Lloyd Jones Cemetery, Spring Green, Wisconsin |
Iṣẹ́ | Òṣèrébinrin |
Ìgbà iṣẹ́ | 1936–1985 |
Political party | Republican |
Olólùfẹ́ | John Hodiak (m. 1946; div. 1953) Randolph Galt (m. 1960; div. 1969) David Klee [1](m. 1977; died 1977) |
Àwọn ọmọ | 3 |
Àwọn olùbátan | Frank Lloyd Wright Lloyd Wright (uncle) John Lloyd Wright Eric Lloyd Wright Elizabeth Wright Ingraham |
Awards | Ebun Akademi (1947) Golden Globe Award for Best Supporting Actress – Motion Picture|Golden Globe Award for Best Supporting Actress (1947) |
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀
àtúnṣeAnne Baxter ni wọ́n bí ní ọjọ́ keje, oṣù kaarun ọdún 1923 ní ìlú Michigan, Indiana si idìlé Catherine Dorothy (née Wright; 1894–1979). Olúlú Westchester County, New York ni wón ti wo dàgbà.
Àwọn Ẹbùn ati Amì Ẹyẹ
àtúnṣeYear | Award | Category | Work | Result |
---|---|---|---|---|
1947 | Golden Globe Award | Best Supporting Actress – Motion Picture | The Razor's Edge | Gbàá |
1946 | Ebun Akademi | Best Supporting Actress[3] | The Razor's Edge | Gbàá |
1951 | Best Actress | All About Eve | Wọ́n pèé | |
1957 | Laurel Award | Topliner Female Dramatic Performance | The Ten Commandments | Gbàá |
1969 | Primetime Emmy Award | Outstanding Single Performance by an Actress in a Leading Role | The Name of the Game ("The Bobby Currier Story") | Wọ́n pèé |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "Actress Anne Baxter Dead at 62". AP NEWS. December 13, 1985. Retrieved August 26, 2022.
- ↑ "- Turner Classic Movies". Turner Classic Movies. August 23, 2022. Retrieved August 26, 2022.
- ↑ "Oscar-Winner Anne Baxter Is Dead at 62". Washington Post. December 13, 1985. Retrieved August 26, 2022.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |