Anny Robert
Anietie “Anny" Robert (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n, oṣù kẹsàn-án, ọdún 1990) jẹ́ Ayàwòrán ní oríẹ̀-èdè Nàìjíríà àti olùdarí oníṣẹ́ ọnà , tó ń gbé ní ìpínlè Niger, Nàìjíría.
Anny Robert | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Anietie " Anny" Robert {28 October 1990}} |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Covenant University |
Iṣẹ́ | Photographer, creative director, graphics artist |
Ìgbà iṣẹ́ | 2014 – present |
Organization | Anny Robert |
Gbajúmọ̀ fún | Portrait, celebrity, and fashion photography |
Website | annyrobert.online |
Ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeRobert kọ́ ẹ̀kó nípa computer science ní iléẹ̀kọ́ gíga Convenant.[1]
Iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeRobert bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí ẹni tó máa ń ṣe gíráfíìsì kí ò ṣẹ̀ wá bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ àwòrá́n yíyà, ní ọdún 2014. Nínú àwọn iṣẹ́ rẹ̀ ni a ti rí àwọn àwòrán èèyàn jàkàn jàkàn bíi Folorunsho Alakija, Davido, Donald Duke, Tony Elumelu, Ice Prince, àti WizKid.[2] Òun ni Alákòóso ilé-iṣẹ́ StudioX, photography studio, ní àjọṣepọ̀ pẹ̀lú Ari Labadi.[3]
Iṣẹ́ Robert's Gẹ́gẹ́ bí ayàwòrán ti jẹ́ kí ó di gbajúgbajà, tí orúkọ rẹ̀ wà lára àwon ayàwòrán tí ó gbajúmọ̀ ní Nàìjíríà àti ilẹ̀ Áfíríkà lápapọ̀ .[4][5][6][7][8][9] [10][11]
Ní ọdún 2020, Robert ṣe adájọ́ fún ìdíje OPPO Mobile's Redefinition Photography, Ní bi tí ó ti fi fọ́tọ̀ yíyà sọ ìtàn ìgbésí ayé àwọn ọ̀dọ́ nílùú Èkó.[12][13][14][15][2]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Nigeria, Guardian (2019-10-28). "Covenant University student wins architecture competition". The Guardian Nigeria News – Nigeria and World News. Retrieved 2023-06-01.
- ↑ 2.0 2.1 Obinna, Emelike (2022-12-23). "The Ascension: A show of creative ingenuity by Anny Robert, others". Businessday NG (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2023-01-19.
- ↑ "Behance-Anny Robert". www.behance.net. Retrieved 2020-07-30.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Akpan, Atai (17 September 2018). "The Man Behind the Lens: Anny Robert". StyleVitae (Style Vitae). http://stylevitae.com/the-man-behind-the-lens-anny-robert/. Retrieved 2020-07-30.
- ↑ Mazibuko, Thobile (2017-11-21). "Five fashion photographers from Africa" (in en). www.africanindy.com. https://www.africanindy.com/culture/five-fashion-photographers-from-africa-12084189. Retrieved 2020-07-30.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Dokpesi, April (2019-05-13). "6 Nigerian photographers you'll be mad you didn't know about". Chase.be. Archived from the original on 2020-02-06. https://web.archive.org/web/20200206200228/http://chase.be/blog/5-nigerian-photographers/. Retrieved 2020-07-30.
- ↑ YOTS (6 May 2016). "Personal Branding Photographers In Nigeria". Official website of Yetunde Shorters. https://www.yetundeshorters.com/top-15-personal-branding-photographers-nigeria-know/. Retrieved 2020-07-30.
- ↑ Demand, Africa (21 June 2018). "10 Amazing African Fashion Photographers". Demand Africa. https://www.demandafrica.com/style/fashion/10-amazing-african-fashion-photographers/. Retrieved 2020-07-30.
- ↑ Rave, Style (18 May 2020). "Famous Photographers of Nigerian Descent You Should Know". Style Rave. https://www.stylerave.com/famous-photographers-of-nigerian-descent/. Retrieved 2020-07-30.
- ↑ Akabogu, Njideka (2 February 2017). "See How Photographer Anny Robert Is Helping A House Help's Modeling Dreams Come True". 234Star. https://234star.com/see-how-photographer-anny-robert-is-helping-a-house-helps-modelling-dreams-come-true/. Retrieved 2020-07-30.
- ↑ "Meet Amaka, a Domestic Help & Aspiring Model transformed through Celeb Photographer Anny Robert's Camera Lens". BellaNaija. 2 February 2017. https://www.bellanaija.com/2017/02/meet-amaka-a-domestic-help-aspiring-model-transformed-through-celeb-photographer-anny-roberts-camera-lens/. Retrieved 2020-07-30.
- ↑ "Three Winners Emerge at OPPO Mobile Redefinition Photography Contest". CFAmedia.ng – Startups | Media | Business | Technology News. 27 February 2020. https://cfamedia.ng/three-winners-oppo-mobile-redefinition-photography-contest/. Retrieved 2020-07-30.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Celebrity Photographer Anny Roberts proves that OPPO F11 Pro is Phone for all Seasons". BellaNaija. 5 June 2019. https://www.bellanaija.com/2019/06/oppo-mobile-anny-roberts-photography/. Retrieved 2020-07-30.
- ↑ Bellanaija (2 February 2017). "Meet Amaka, a Domestic Help & Aspiring Model transformed through Celeb Photographer Anny Robert's Camera Lens". BellaNaija. https://www.bellanaija.com/2017/02/meet-amaka-a-domestic-help-aspiring-model-transformed-through-celeb-photographer-anny-roberts-camera-lens/. Retrieved 2020-07-30.
- ↑ "Anny Robert's Women for Women Campaign is Celebrating the Feminists Doing the Hard Work of Fighting for Basic Human Rights". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-08-24. Retrieved 2023-01-19.