Antar Laniyan
Antar Laniyan jẹ́ ògbóǹtarìgì òṣèrékúnrin, aṣàgbéjáde eré àti olùdarí eré ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1]
Antar Laniyan | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Osogbo, Osun, Nigeria |
Ẹ̀kọ́ | University of Ibadan, BA in theatre arts |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Ibadan |
Iṣẹ́ | Film actor and producer |
Ìgbà iṣẹ́ | 1981–present |
Notable work | Sango |
Ìgbésí ayé rẹ̀
àtúnṣeÌlú Òṣogbo tó jẹ́ olú-ìlú Ọ̀ṣun, ní apá Ìwọ-oòrùn ilẹ̀ Nàìjíríà ni wọ́n bí Laniyan sí.[2] Ìlé-ìwé Baptist Secondary School ni ó ti gba ìwé-ẹ̀rí ( WAEC ),[3] ní Ìpínlẹ̀ Èkó kó tó di pé ó wá lọ sí Yunifásítì ìlú Ìbàdàn, láti lọ kọ́ ẹ̀kọ́ nípa iṣẹ́ tíátà.[4]
Iṣé tó yàn láàyò
àtúnṣeLaniyan bẹ̀rẹ̀ iṣé eré-ṣíṣe ní ọdún 1981, ẹ̀dá-ìtàn àkọ́kọ́ tó sì kọ́kọ́ ṣe ni ''major general'' nínú fíìmù kan tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Everybody wants to know lákòokòtó wà ní Kakaki Art Squad.[5][6] Ó ti kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù orílẹ̀-èdè Nàìjíríà bí i Sango, èyí tó jẹ́ fíìmù tí Wale Ogunyemi ṣe, tí Obafemi Lasode sì jẹ́ olùdarí eré náà.[7][8] Òun ní olùdarí tó darí apá kìíní ti fíìmù Super Story, tí Wale Adenuga ṣàgbéjáde ní ọdún 2000, tó sì ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ.[9] Òun sì ló tún darí fíìmù Oh Daughter àti This Life tí Wale Adenuga bákan náà ṣàgbéjáde.[10]
Àṣààyàn àwọn fíìmù rẹ̀
àtúnṣe- Sango (1997)
- Super Story (episode 1)
- Kakanfo (2020)
- Lucifer (2019)
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Empty citation (help)
- ↑ "Antar Laniyan - Nigerian Entertainment Today - Nigeria's Number 1 Entertainment Daily". thenet.ng. Retrieved 13 February 2015.
- ↑ "Home | West Africa Examination Council Nigeria". www.waecnigeria.org. Retrieved 2022-10-15.
- ↑ Empty citation (help)
- ↑ "Most people think I'm gay -Antar Laniyan – Nigerian Tribune - Nollywood Express". Nollywood Express. Archived from the original on 13 February 2015. Retrieved 13 February 2015.
- ↑ "Mega Icon Magazine My Life Time Ambition- Antar Laniyan.". Mega Icon Magazine. Archived from the original on 13 February 2015. Retrieved 13 February 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Antar Laniyan - nigeriafilms.com". nigeriafilms.com. Retrieved 13 February 2015.
- ↑ Lindfors, Bernth (2003). Black African Literature in English, 1997-1999. James Currey Publishers. ISBN 9780852555750. https://books.google.com/books?id=rAUbyu1wRCsC&q=Sango+film+scripted+by+Wale+Ogunyemi&pg=PA8. Retrieved 13 February 2015.
- ↑ "I AM ONLY INTERESTED IN TAPPING YOUR TALENT-----ANTAR LANIYAN". World News. Retrieved 13 February 2015.
- ↑ "I was named after an animal - Antar Laniyan - Vanguard News". Vanguard News. Retrieved 13 February 2015.