Antoine Gizenga

Oloṣelu Kongo

Antoine Gizenga (ojoibi 5 Osu Kewa 1925) je oloselu ara Kongo (OOTK) to di Alakoso Agba ti OOTK lati 30 Osu Kejila 2006[1] di 10 Osu Kewa 2008.[2] Ohun ni Akowe Agba Egbe Lumumbisti Piparapo (Parti Lumumbiste Unifié, PALU).

Antoine Gizenga
Alakoso Agba OOT ile Kongo
In office
30 December 2006 – 10 October 2008
ÀàrẹJoseph Kabila
AsíwájúLikulia Bolongo
Arọ́pòAdolphe Muzito
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí5 Oṣù Kẹ̀wá 1925 (1925-10-05) (ọmọ ọdún 98)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPALU