Antonio Fargas

Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America

Antonio Juan Fargas (ọjọ́ìbí August 14, 1946) ni òṣeré ará Amẹ́ríkà tó gbajúmọ̀ fún àwọn ìṣeré rẹ̀ nínú àwọn fílmu blaxploitation ní ìgbà 1970, àti fún ìṣeré rẹ̀ bíi Huggy Bear nínú eré tẹlifísàn ìgbà 1970 Starsky & Hutch.

Antonio Fargas
Fargas at the 2018 East Coast Comicon
in Secaucus, New Jersey
Ọjọ́ìbíAntonio Juan Fargas
14 Oṣù Kẹjọ 1946 (1946-08-14) (ọmọ ọdún 78)
New York City, New York, U.S.
Iṣẹ́Òṣeré
Ìgbà iṣẹ́1963–present
Gbajúmọ̀ fúnHuggy Bear – Starsky & Hutch
Olólùfẹ́
Taylor Hastie
(m. 1979; div. 1988)

Sandra Reed (??–present)
Àwọn ọmọ4, incl. Justin Fargas
Websitewww.AntonioFargas.com

Ìgbà èwe

àtúnṣe

Wọ́n bí Fargas ní Ìlú New York sí Mildred (orúkọ ìdílé Bailey) àti Manuel Fargas; ó jẹ́ ìkan nínú àwọn ọmọ 11.[1][2] Bàbá rẹ̀ wá láti Puerto Rico sí Ìlú New York fún iṣẹ́. Ìyá rẹ̀ wá láti Trinidad àti Tobago.[2] Ó dàgbà ní àdúgbò Spanish Harlem, New York, Fargas parí ní ilé-ẹ̀kọ́ Fashion Industries High School ní 1965.[3]

Iṣẹ́ eré

àtúnṣe

Ìṣeré Fargas bẹ̀rẹ̀ nínú fílmù kọ́mẹ́dì Putney Swope (1969). Lẹ̀yìn náà ló kópa nínú àwọn fílmù blaxploitation ìgbà 1970s, bíi Across 110th Street (1972) àti Foxy Brown (1974).

Ìgbésíayé

àtúnṣe

Ọmọ ọkùnrin Fargas Justin Fargas, tó parí ní University of Southern California jẹ́ agbábọ́ọ̀lù NFL tẹ́lẹ̀ fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Oakland Raiders.[4]

Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Antonio Fargas Biography". Film Reference. 2008. Retrieved January 19, 2017. 
  2. 2.0 2.1 "Antonio Fargas Interview". Memorable TV. 2008. Archived from the original on July 21, 2008. Retrieved January 19, 2017. 
  3. Reyes, Luis (2000). Hispanics in Hollywood: A Celebration of 100 Years in Film and Television. Lone Eagle. pp. 464. ISBN 9781580650250. 
  4. Rabalais, Scott (September 7, 2014). "LSU's Nikki Caldwell makes it official with longtime fiancé Justin Fargas". The Advocate. Archived from the original on July 2, 2016. https://web.archive.org/web/20160702225729/http://theadvocate.com/sports/lsu/10192440-171/lsus-nikki-caldwell-makes-it.