Arturo Frondizi
Arturo Frondizi je Aare orile-ede Argentina tele.
Arturo Frondizi | |
---|---|
arẹ orílè-èdè Argentina | |
In office May 1, 1958 – March 29, 1962 | |
Vice President | Alejandro Gómez (May–Nov 1958) None (1958–1962) |
Asíwájú | Pedro Eugenio Aramburu |
Arọ́pò | José María Guido |
National Deputy | |
In office June 4, 1946 – June 4, 1952 | |
Constituency | Buenos Aires |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Arturo Frondizi Ércoli October 28, 1908 Paso de los Libres, Corrientes, Argentina |
Aláìsí | April 18, 1995 Buenos Aires, Argentina | (ọmọ ọdún 86)
Resting place | Basílica de la Inmaculada Concepción, Entre Ríos, Argentina |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Argentine |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Radical Civic Union (1932–1956) Intransigent Radical Civic Union (1956–1963) Integration and Development Movement(1963–1986) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Elena Luisa María Faggionato (m. 1933; died 1991) |
Àwọn ọmọ | Elena Frondizi Faggionato |
Alma mater | University of Buenos Aires |
Profession | agbẹ́jọ̀ro |
Signature |
Arturo Frondizi Ércoli (October 28, 1908 – April 18, 1995) jẹ́ agbẹjọro, oniroyin,olùkó, olóṣèlú ará orílè-èdè Argentina journalist, tì wọ̀n sípò arẹ orílè-èdè Argentina láàrin ọjọ́ kinní oṣù kàrún ọdún 1958 sí ọjọ́ kokandinlogbon oṣù kẹta ọdún 1962 nígbà tí wón gbà ijọba lọ́wọ́ rẹ̀.
Ìgbésíayé
àtúnṣeWón bí Arturo Frondizi ní ìlú Paso de los Libres, Argentina ní ọdun 1908. Ọmọ Isabella Ércoli de Frondizi ati Giulio Frondizi ní se.
Awọn amì ẹ̀yẹ
àtúnṣeẸ̀yẹ
àtúnṣeAmi ẹyẹ | orílè-èdè | Ọjọ́ | |
---|---|---|---|
Grand Collar of the Order of the Condor of the Andes | Bolivia | 8 July 1961 | |
Collar of the Order of Merit | Chile | 1 July 1958 | |
Knight Grand Cross of the Order of the Legion of Honour | France | 8 May 1960 | |
Grand Cross Special Class of the Order of Merit of the Federal Republic of Germany | Germany | June 1960 | |
Knight Grand Cross with collar of the Order of Merit of the Italian Republic | Italy | 11 June 1960 | |
Grand Cross of the Order of the Chrysanthemum | Japan | 14 December 1961 | |
Collar of the Order of the Aztec Eagle | Mexico | 21 January 1960 | |
Grand Cross of the Order of the Netherlands Lion | Netherlands | 1 July 1960 | |
Grand Cross of the Order of the Sun of Peru | Peru | 17 April 1958 | |
Knight of the Collar of the Order of Isabella the Catholic | Spain | 7 July 1960 | |
Knight Grand Cross of the Order of Chula Chom Klao[1] | Thailand | 8 December 1961 | |
Honorary Knight Grand Cross of the Order of St Michael and St George | United Kingdom | 4 July 1960 |
Ami ẹkọ idanilola
àtúnṣe- Peru: University of San Marcos, 1958
- Hawaii: University of Hawái, 1961
- Italy: University of Perugia, 1960
- Japan: Waseda University, 1961
- Spain: University of Madrid, 1960
- Thailand: Thammasat University, 1961
- United States: Fordham university, 1959
Àmì ẹ̀yẹ ati dídágánjíá
àtúnṣe- Argentina: Konex of honour, 1998
- Japan: Key to the city of tokyo, 1960
- Spain: Key to the city of madrid, 1960
- Uruguay: Uruguayan Parliamentary Distinction, 1958
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ ราชกิจจานุเบกษา, ประกาศสำนักนายกรัฐมนตรี เรื่อง พระราชทานเครื่องราชอิสริยาภรณ์ Archived 2016-03-04 at the Wayback Machine., เล่ม 79, ตอน 22 ง, 6 มีนาคม พ.ศ. 2505, หน้า 558