Asam pedas

Oúnjẹ Minangkabau

Asam pedas (Jawi: Àdàkọ:Script/Arabic; Minangkabau: asam padeh; "ohun tí ó korò àti ohun tí ó ta") ó jẹ́ ọbẹ̀ ẹja tí ó korò tí ó sì ta pẹ̀lú ti àwọn tí ó ń gbé Maritime ní gúúsù ìlà-oòrùn ilẹ̀ Asia.[5] Wọ́n gbà pé Asam pedas jẹ́ oúnjẹ tí ó wá láti ara àwọn oúnjẹ Minangkabau apá ìwọ̀-oòrùn Sumatra, Indonesia tí ó sì ti tàn káàkiri gbogbo ilẹ̀ Sumatra, Borneo àti Malay Peninsula.[6]

Asam pedas
Àdàkọ:Script/Arabic
Ambu-ambu asam padeh, a Padang-style asam pedas ikan tongkol (mackerel tuna)
CourseMain course
Place of originIndonesia, Malaysia[1][2][3]
Region or stateSumatra, Malay Peninsula
Associated national cuisineIndonesia, Malaysia[4] and Singapore
Serving temperatureHot or room temperature
Main ingredientsFish cooked in sour and hot sauce
Àdàkọ:Wikibooks-inline 

Àwọn ẹkùn tí a ti lè ri

àtúnṣe
 
Asam padeh baung from Riau on an Indonesian stamp

Ọbẹ̀ ẹja yìí jẹ́ ti àwọn ará Malay Archipelago,[7] èyí tí wọ́n mọ̀ káàkiri ní Sumatra, Borneo àti ní Malay Peninsula. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn oúnjẹ ìbílẹ̀ Minangkabau àti Malay. Oúnjẹ Minang asam padeh jẹ́ èyí tí wọ́n sáábà máa ń jẹ ní ilé oúnjẹ ti PadangIndonesia, Malaysia àti Singapore.[5]

Ó ti jẹ́ ọ̀kan lára àwọn oúnjẹ ìbílẹ̀ tí àwọn ènìyàn Malay tí wọ́n wá láti ìwọ̀-oòrùn etíkun Sumatra—Jambi, Riau, Riau Islands, àti ní àríwá bíi Aceh àti ní gbogbo Strait of Malacca tí ó wà ní Johore, Malacca,[8] Singapore, àti ní coastal Borneo, pàápàá jùlọ ní Pontianak èyí tí ó wà ní ìwọ̀-oòrùn Kalimantan.[9] Àwọn ohun èlò tí wọ́n ń lò ní àwọn àgbègbè kan lè yàtọ̀ sí ti èkejì.[citation needed]

Bí a se ń sè é

àtúnṣe

Àdàkọ:More citations needed section

 
Abọ́ oúnjẹ Mempawah asam pedas, West Kalimantan.

Àwọn ohun ìsebẹ́ tí ó gbajúmọ̀ tí a sáábà máa ń lò fún asam pedas sáábà máa ń jẹ́ àwọn ẹja òkun tàbí tí inú omi tí ó bá mọ́. Wọ́n máa ń sè wọ́n ní asam (tamarind) ohun mímu ẹlẹ́rìndòdò, ata, àti àwọn ohun ìsebẹ̀ mìíràn.

Àwọn ẹja odò gẹ́gẹ́ bíi mackerel, mackerel tuna, tuna, skipjack tuna, red snapper, gourami, pangasius, hemibagrus tàbí cuttlefish — bóyá odidi ni tàbí orí ẹja nìkan jẹ́ èyí tí wọ́n máa yí mọ́ ata láti fi se ọbẹ̀ ẹja. Ó ṣe pàtàkì kí ó jẹ́ pé kò sí nǹkan kan tí ó máa mú ẹja náà rún, kí ó ba à le ṣe é pín, ìdí nìyí tí wọ́n fi máa ń fi ẹja sí i ní ẹ̀yìn lẹ́yìn.[10]

Indonesia, ẹja tí ó gbajúmọ̀ tí wọ́n máa ń lò fún asam pedas ni tongkol (mackerel tuna). Ní Lingga, wọ́n máa ń jẹ oúnjẹ yìí pẹ̀lú sago (lempeng sagu) láti fi di ipò ìrẹsì tí wọ́n máa ń lò ní àwọn ìletò mìíràn. [11]

Kaeng som jẹ́ oúnjẹ àwọn Thai èyí tí ó fi ara jọ asam pedas.[12]Bengal, India oúnjẹ kan náà wà tí ó fi ara pẹ́ asam pedas òun ni Macher tak (ẹja tí ó korò).

Wò pẹ̀lú

àtúnṣe

Àdàkọ:Portal box

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe


  1. Boi, Lee Geok (15 September 2017) (in en). Asian Seafood. Marshall Cavendish International Asia Pte Ltd. ISBN 978-981-4794-08-4. https://books.google.com/books?id=OuBBDwAAQBAJ&q=asam+pedas+Indonesian+sour+and+spicy+dish&pg=PT49. 
  2. "Ikan Asam Pedas Pontianak, Jenis menu masakan masyarakat Melayu" (in id). 2 November 2020. https://kebudayaan.kemdikbud.go.id/ditwdb/ikan-asam-pedas-pontianak-jenis-menu-masakan-masyarakat-melayu/. 
  3. Arman, Dedi (26 May 2019). "Pedasnya Ikan Asam Pedas Melayu" (in id). https://kebudayaan.kemdikbud.go.id/bpnbkepri/pedasnya-ikan-asam-pedas-melayu/. 
  4. "3 Most Popular Western Malaysian Seafood Dishes". 
  5. 5.0 5.1 Donny Syofyan (24 November 2013). "By the way ... I just can't live without Padang food". The Jakarta Post. http://www.thejakartapost.com/news/2013/11/24/by-way-i-just-can-t-live-without-padang-food.html. 
  6. "Serba-serbi RM Padang: Dari Rendang sampai Rahasia Saji" (in id). 2020-12-28. https://jeo.kompas.com/serba-serbi-rm-padangdari-rendang-sampai-rahasia-saji. 
  7. Jais, Ahmad Sahir (September 2016). "Deconstructing Malay Delicacies " Asam Pedas " : Critical Ingredients and Flavor Profile" – via ResearchGate. 
  8. "Asam pedas goes global | The Star". www.thestar.com.my. Retrieved 2020-09-22. 
  9. ditwdb (2019-11-02). "Ikan Asam Pedas Pontianak, Jenis menu masakan masyarakat Melayu". Direktorat Warisan dan Diplomasi Budaya (in Èdè Indonéṣíà). Retrieved 2020-09-24. 
  10. "Asam Pedas". Tastefood. Archived from the original on 2012-01-03.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  11. Faris Joraimi (Apr–Jun 2021). "Mother Island: Finding Singapore's Past in Pulau Lingga". BiblioAsia (National Library Board, Singapore) 17 (4): 30–35. https://biblioasia.nlb.gov.sg/vol-17/issue-4/jan-mar-2022/. 
  12. "Kaeng-som, a Thai culinary classic". 

Àdàkọ:Indonesian cuisine Àdàkọ:Malaysian cuisine Àdàkọ:Singaporean cuisine