Askimam jẹ́ ojú-òpó wẹ́ẹ̀bù tí ń pèsè àlàyé nípa ẹ̀sìn Mùsùlùmí. Ọ̀mọ̀wé nípa ẹ̀kọ́ Mùsùlùmí kan tó jẹ́ ọmọ South Africa, àti adájọ́ kan, tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ebrahim Desai ló ṣe ìdásílẹ̀ ojú-òpó yìí, ní ọún 2000. Àwọn ìdáhùn orí ojú-òpó yìí jẹ́ àfihàn òfin nípa ìwòye Hanafi Deobandi. Ó ti ní ipa rẹpẹtẹ, ó sì gbajúmọ̀ jú àwọn ojú-òpó mìíràn lọ, bí i ti Al-Azhar University àti àwọn yòókù.

Askimam.org
Askimam (website) logo.jpg
Askimam website (screenshot) 16 July 2021.jpg
Screenshot of Askimam's Belief Category on 16 July 2021
URLaskimam.org/
Commercial?No
Type of siteIslamic, Hanafi, Legal/Religious
RegistrationRequired
Created byEbrahim Desai
Launched2000; ọdún 24 sẹ́yìn (2000) Àdàkọ:Bulleted list
Current statusActive

Ọmọ̀wé kan, tó jẹ́ onímọ̀ Mùsùlùmí, láti South Africa àti adájọ́ Ebrahim Desai, tó fìgbà kan darí Darul Ifta ti Madrassah In'aamiyyah.[1] Èrò kan ni pé ojú-òpó yìí jẹ́ ìmúdójúìwọ̀n ojú-òpó mìíràn, tí a mọ̀ sí ask-imam.com tí ó bẹ̀rẹ̀ ní ọdún 2000. Wọ́n ṣe ìásílẹ̀ Askimam.org ní ọdún 2004.[2] Èròǹgbà wọn ni pé kí wọ́n lo ojú-òpó yìí láti fi ṣe ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ènìyàn tó nífẹ̀ẹ́ láti mọ̀ nípa ẹ̀sìn Mùsùlùmí, àti láti dáhùn àwọn ìbéèrè wọn.[3] Ojú-òpó náà ní tó àṣẹ 4686, ní oṣù kẹjọ ọdún 2002. [4]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Mohiuddin, Afshan; Suleman, Mehrunisha; Rasheed, Shoaib; Padela, Aasim I. (2020). "When can Muslims withdraw or withhold life support? A narrative review of Islamic juridical rulings". Global Bioethics 31 (1): 29–46. doi:10.1080/11287462.2020.1736243. PMC 7144300. PMID 32284707. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=7144300. 
  2. Šisler 2009, p. 65.
  3. Šisler 2009.
  4. Bunt 2003.