Asmaa Abulyazeid
Asma Abulyazeid (èdè lárúbáwá: أسماء أبو اليزيد) jẹ́ akorin àti òṣèré tí ó wá
Asmaa Abulyazeid | |
---|---|
Orúkọ àbísọ | أسماء أبو اليزيد |
Ọjọ́ìbí | Cairo, Egypt |
Orílẹ̀-èdè | Egyptian |
Ìgbà iṣẹ́ | 2011 - titi di asikoyi |
á laìlúiu Egypt ,[1] ó kẹ́kọ̀ọ́ ìtanràn àwòrán ode kó pa nínú eré orí ìtàgé ní Tíátà Hanager ó sì díje fún àmì ẹ̀yẹ Sheikh Sultan Al Qasimi fún eré ìtàgé tí ó dára jùlọ ní ọdún 2016.
Ó fa àkíyèsí sí ara rẹ̀ nítorí ipa tí ó kó nínú jara tẹlifísàn gẹ́gẹ́ bí "Tọka" nínú "This evening" ní ọdún 2016, ó kópa nínú fíìmù oríṣi, ó tún wà pẹ̀lú ẹgbẹ́ orin "Bahjja" ó sì ti ṣe àwọn aṣàmúlò ọ̀rọ̀ orísirísi.[2][3]
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Ayé Rẹ̀
àtúnṣeÌlú Cairo, ní Egypt ni wọ́n bí Asmaa sí. Bàbá rẹ̀ wá láti ìlú Cairo, ìyá rẹ̀ sì wá láti Sharqia. Asmaa ti fẹ́ràn kí ó ma ṣe eré láti ìgbà ọmọdé rẹ̀ sùgbọ́n kò rí eré ṣe nítorí pé kò sí eré ìtàgé ṣíṣe ní ilé-ẹ̀kọ́ ti ó lọ, ṣùgbọ́n lẹ́hìn tí ó dé ilé-ẹ̀kọ́ gíga ó rí ẹgbẹ́ tíátà, ó sì darapọ̀ mọ́ wọn nípasẹ̀ ẹgbẹ́ Tíátà Atelier.
Ní ìgbà tí ó darapọ̀ mọ́"Tíátà Atelier" ó kọ́ iṣẹ́ lọ́wọ́ Olùdárí Shadi Daly ó sì ṣe oríṣiríṣi ìdíje, èyí tí ó ṣe ní gbẹ̀yìn ni "Magic Mix of Happiness" tí ó díje nínú Arab Theater Festival fún àmì ẹ̀yẹ "Sheikh Sultan Al Qasimi" fún ẹgbẹ́ eré ìtàgé Arab ní ọdún 2016.
Eré ìtàgé tí ó kọ́kọ́ ṣe ni èyí tí ó ṣe ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga, ní abẹ́ àkòrí "Life is Beautiful In Fine Arts", lẹ́hìn ìgbà náà, ó kópa nínú eré orí ìtàgé tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ "Antar Stable" ti Bayoumi Fouad ṣe olùdárí rẹ̀.
Ní ọdún 2014, ó kópa nínú jara tẹlifísàn "I Loved" èyí tí Maryam Al Ahmadi ṣùgbọ́n ipa kékeré ni ó kó níbẹ̀.
A yan kalẹ̀ nípasẹ̀ olùdáṣiṣẹ́ Ahmed Medhat Sadeq, tí ó jẹ́ olùdárí Tamer Mohsen, láti ṣe ipa ti "Toka" àti lẹ́hìn tí ó ja gèrè ní àwọn ìdánwò, èyítí ó yọrí sí ipa tí ó gbà. [4]
Ẹ̀rù máa ń bàá láti dúró sí iwájú kámẹ́rà, nítorí kò ní ìgboyà láti kó ipa rẹ̀ nínú eré náà. Ó fẹ́ràn ipa Taqa tí ó kó, nítorí ipa náà jẹ́ titi àláàánú, ṣùgbọ́n ó ní agbára.[5]
Abulyazeid ṣe olùdárí "Melodrama" ní ọdún 2013, ó tún kópa nínú "Habhan", ó tún ṣe olùdárí Shadi Daly nínú eré "Dream Plastic" tí ó kópa nínú. Ó tún ṣe "Made in China" àti The Revolution of the Dead.[6][7][8]
Àwọn Iṣẹ́ Rẹ̀ Àti Àwọn Fíìmù Rẹ̀
àtúnṣe- |
Àwọn Eréàtúnṣe
|
Eré Tẹlifísànàtúnṣe
Àwọn Eré Ìtàgéàtúnṣe
|
Àwọn Àmì Ẹ̀yẹ
àtúnṣe- Òṣèré tí ó dára jùlọ ní "Elia Short Film Festival " ní ọdún 2019.[10]
Àwọn Ìtọ́ka Sí
àtúnṣe- ↑ https://www.elcinema.com/en/person/2084160
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2019-10-11. Retrieved 2020-10-12.
- ↑ https://www.albawaba.com/slideshow/asma-abulyazeid-aphrodite-photoshoot-year-1209246
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2019-10-11. Retrieved 2020-10-12.
- ↑ https://scoopempire.com/is-it-possible-for-asma-abulyazeid-to-take-a-photo-and-not-look-good/
- ↑ Elfeqy, Salma (2018-05-28). "The Amazing Galila or Should We Say Asmaa Abulyazeid". Identity Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-10-11.
- ↑ القاهرة – "الحياة" (2019-07-21). "أسماء أبو اليزيد تخوض بطولة "شكة دبوس"". Hayat (in Arabic). Archived from the original on 2019-10-11. Retrieved 2019-10-11.
- ↑ "أسماء أبو اليزيد: أنا ممثلة.. والرقص والغناء "كماليات" - بوابة الشروق". www.shorouknews.com (in Èdè Árábìkì). Retrieved 2019-10-11.
- ↑ https://egyptindependent.com/egyptian-movie-al-mamr-to-air-on-tv-channels-on-occasion-of-october-war/
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2019-10-11. Retrieved 2020-10-12.
Awọn ọna asopọ ita
àtúnṣe- Asmaa Abulyazeid lórí Facebook