Aso Villa
Aso villa jé ilè ibùgbé fún Ááre orílè-èdè Nàìjíríà láti odún 1991(Nígbà tí Olori ologun Ibrahim Badamasi Babangida so ìlú Abuja di Olú ìlú Nàìjíríà). Aso villa wa ní Ìlú Abuja, àwon olùgbé re si ni Àárè Muhammadu Buhari àti idile rè[1]
Aso Villa | |
---|---|
![]() Àwòrán inú Aso Villa | |
Building | |
Architectural style | Neoclassical, Palladian |
Location | Yakubu Gowon Crescent, The Three Arms Zone, Asokoro, Abuja, FCT, Nigeria |
Owner | Federal Government of Nigeria |
Current tenants | Muhammadu Buhari, ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti ìdílé rẹ̀ |
Coordinates | 9°03′44″N 7°31′07″E / 9.062270°N 7.518532°ECoordinates: 9°03′44″N 7°31′07″E / 9.062270°N 7.518532°E |
Construction | |
Started | Oṣù Kẹ̀wá 13, 1989 |
Completed | Oṣù Kọkànlá 1, 1991 |
Kíkó Aso Villa bere ni ojo Ketala osu kewa odún 1989, ásì pari kíkó rè ní ojo kini, osu kokanla tí odún 1991[1]
Àwon Ìtókasí
àtúnṣe- "The Villa – The Statehouse, Abuja". The Statehouse, Abuja. 2018-01-13. Archived from the original on 2023-04-08. Retrieved 2022-02-24.
- "Aso Villa". Wikipedia. 2005-08-18. Retrieved 2022-02-24.
- ↑ 1.0 1.1 "The Villa – The Statehouse, Abuja". The Statehouse, Abuja. 2018-01-13. Archived from the original on 2023-04-08. Retrieved 2023-04-07.