Awa Traoré
Awa Traoré (Èdè Lárúbáwá : أوا تراوري), jẹ́ òṣèré fíímù àti onkọ̀wé ní ìlú Ḿalì.[1]
Awa Traoré أوا تراوري | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Awa Traoré Mali |
Orílẹ̀-èdè | Malian |
Iṣẹ́ | Director, assistant director, composer, screenwriter |
Ìgbà iṣẹ́ | 1995–present |
Iṣẹ́
àtúnṣeTraoré bẹ̀rẹ̀ eré síse rẹ̀ pẹ̀lú fíímù L'enfant noir ní ọdún1995. Lẹ́hìnńà ó ṣiṣẹ́ bí ọdẹ ní fíímù ránpẹ́ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Denko èyí tí Mohamed Camara se adarí rẹ̀ ní ọdún 1993. Fíímù náà gba ìyìn pàtàkì àti àmì ẹ̀yẹ Grand Prix níbi ayẹyẹ Clermont-Ferrand International Short Film Festival[2], ó tún gba ẹ̀bùn fún fíímù ránpẹ́ tí ó dára jùlọ níbi ayẹyẹ Friborg International Film Festival àti àmì ẹ̀yẹ Golden Danzante níbi ayẹyẹ Huesca Film Festival.[3]
Àṣàyàn àwọn eré rẹ̀
àtúnṣeỌd́un | Àkọ́lé eré | Ipa tí ó kó |
---|---|---|
1995 | L'enfant noir | Actress: La chasseresse |
1993 | Denko | Actress: The huntress |
2011 | Une journée avec | Director, writer |
2011 | Correspondances | Assistant director |
2009 | Notre pain capital | Composer |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Awa Traoré". spla. Retrieved 9 October 2020.
- ↑ Nesselson, Lisa (2000). "Clermont-Ferrand Festival of Short Films". FilmFestivals.com. Archived from the original on 2011-06-04. Retrieved 5 February 2010. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "37 Huesca International Film Festival". Huesca Film Festival. 2009. Archived from the original on 2010-05-21. Retrieved 5 February 2010. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)