Mali
Mali, fun tonibise bi Olominira ile Mali (Faransé: République du Mali), je orile-ede tileyika ni Apaiwoorun Afrika. Mali ni bode mo Algeria ni ariwa, Nijer ni ilaorun, Burkina Faso ati Côte d'Ivoire ni guusu, Guinea ni guusu-iwoorun, ati Senegal ati Mauritania ni iwoorun. Itobi re fi die ju 1,240,000 km² lo pelu iye awon eniyan to ju egbegberun 14 lo. Oluilu re wa ni Bamako.
Olómìnira ilẹ̀ Málì Republic of Mali République du Mali
| |
---|---|
Motto: "Un peuple, un but, une foi" "One people, one goal, one faith" | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Bamako |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | French |
Vernacular languages | Bambara |
Orúkọ aráàlú | Malian |
Ìjọba | Semi-presidential republic |
• Aare | Assimi Goïta |
Choguel Kokalla Maïga | |
Ilominira latowo Fransi | |
• Kikede | September 22, 1960 |
Ìtóbi | |
• Total | 1,240,192 km2 (478,841 sq mi) (24th) |
• Omi (%) | 1.6 |
Alábùgbé | |
• April 2009 census | 14,517,176[2] (67th) |
• Ìdìmọ́ra | 11.7/km2 (30.3/sq mi) (215th) |
GDP (PPP) | 2008 estimate |
• Total | $15.084 billion[3] |
• Per capita | $1,129[3] |
GDP (nominal) | 2008 estimate |
• Total | $8.774 billion[3] |
• Per capita | $656[3] |
Gini (1994) | 50.5 high |
HDI (2007) | ▼ 0.371 Error: Invalid HDI value · 178rd |
Owóníná | West African CFA franc (XOF) |
Ibi àkókò | UTC+0 (GMT) |
• Ìgbà oru (DST) | UTC+0 (not observed) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | otun[4] |
Àmì tẹlifóònù | 223 |
ISO 3166 code | ML |
Internet TLD | .ml |
Mali ni agbegbe mejo be sini awon bode re ni ariwa sun de arin Sahara, nigbati agbegbe apaguusu, nibi ti opolopo eniyan ngbe, ni awon odo Niger ati Sénégal. Ise agbe ati ise apeja ni won se ju nibe. Awon ohun alumoni Mali ni wura, uraniomu, ati iyo. Mali je ikan ninu awon orile-ede to je talaka julo mi agbaye.
Present-day Mali oni fi igba kan wa ni apa awon ile obaluaye meta ti Iwoorun Afrika to n dari idunadura kiri Sahara: Ile Obaluaye Ghana, ile Obaluaye Mali (nibiti orile-ede Mali ti gba oruko re), ati Ile Obaluaye Songhai. Ni opin awon odun 1800, Mali bo sowo awon ara Fransi, o di apa Sudan Fransi. Mali gba ilominira ni 1959 lapapo mo Senegal, gege bi Ile Apapo Mali. Leyin odun kan, Ile Apapo Mali di orile-ede alominira ile Mali. Leyin igba pipe ijoba egbe oloselu-kan, ifipagbajoba ni 1991 mu ilana-ibagbepo titun jade ati idasile Mali gege bi orile-ede toseluaralu egbe oloselu-pupo.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Presidency of Mali: Symboles de la République, L’Hymne National du Mali
- ↑ "Mali preliminary 2009 census". Institut National de la Statistique. Archived from the original on April 18, 2010. Retrieved January 12, 2010.
- ↑ 3.0 3.1 3.2 3.3 "Mali". International Monetary Fund. Retrieved 2009-10-01.
- ↑ Which side of the road do they drive on? Brian Lucas. August 2005. Retrieved 2009-01-28