Awka
Awka (Igbo: Ọka)[1] ní olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Anambra, Nàìjíríà. Wọ́n sọ ìlú náà di olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Anambra ní 21 August 1991, nígbà tí wón ya Ìpínlẹ̀ Anambra kúrò lára Ìpínlẹ̀ Enugu. Gẹ́gẹ́ bí abayori ìkànìyàn ọdún 2006 ní Nàìjíríà, àwọn olùgbé Akwa tó 301,657. Ìpínlẹ̀ Awka wà láàrin Onitsha àti Enugu.
Awka | |
---|---|
Awka city | |
Country | Nigeria |
Ipinle | Ipinle Anambra |
6°12′25″N 7°04′04″E / 6.20694°N 7.06778°E
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn Ìtókasí
àtúnṣe- ↑ Egbokhare, Francis O.; Oyetade, S. Oluwole (2002). Harmonization and standardization of Nigerian languages. CASAS. p. 106. ISBN 1-919799-70-2.