Èdè Ígbò

(Àtúnjúwe láti Èdè Igbo)

Kini Èdè Igbo?

àtúnṣe
Igbo
Igbo
Sísọ nísoutheastern Nigeria
AgbègbèNigeria and other countries (transplants)
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀20-35 million
Èdè ìbátan
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-1ig
ISO 639-2ibo
ISO 639-3ibo
Èdè Ígbò

Ède Igbo je èdè ti awon èniyàn ni guusu ila-oorun ti Nigeria, awa n pe ilè yii, ilè Igbo.

Melo ni èniyàn n so Igbo?

àtúnṣe

30-45 egberun egberun (millionu) èniyàn n so èdè Igbo.

Se o je otito pé èdè Igbo fi ku?

àtúnṣe

Bee ni, èdè Igbo fi ku. Sùgbon, ilè Igbo ti gbiyanju lati soji èdè Igbo, ati o sisè.

Èése èdè Igbo fi ku?

àtúnṣe

Èdè Igbo fi ku, nitori dìè awon èniyàn Igbo, won ro pé èdè Igbo, o ko se pataki. Won ro pé èdè Igbo je fun awon alailẹkọ.

Se èdè Igbo je dandan ibikan kan?

àtúnṣe
 
Aworan aye ti Ilè Igbo

Bee ni, Igbo je dandan ni ipinle Abia, Anambra, Ebonyi, ati Imo.