Ayọ̀ Bámgbóṣé

(Àtúnjúwe láti Ayọ̀ Bangbóṣé)

Ayọ̀ríndé Bámgbóṣé (ojoibi ọjọ́ 27 oṣù Kíní, ọdún 1932) jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n onímọ̀ ẹ̀dá èdè, tí ó sì tún jẹ́ ẹni àkọ́kọ́ tí ó gba oyò ọ̀jọ̀gbọ́n àkọ́kọ́ nínú ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ẹ̀dá èdè ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó ti ṣiṣẹ́ ribi ribi nínú ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ẹ̀dá èdè, tí ó sì ti di ìlú mọ̀ọ́ká àti gbajú-gbajà láàrin àwọn akẹgbẹ́ rẹ̀ lágbo ìmọ̀ ẹ̀dá èdè.[1]

Ayo Bamgbose
Ọjọ́ìbíAyọ̀rìndé Bámgbóṣé
(1932-01-27)27 Oṣù Kínní 1932 (age 86)
Odopotu, Ijebu Ode, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaUniversity College London, University of Edinburgh
Iṣẹ́Linguist, Professor, Scholar
Ọmọ ìlúOdopotu


Àwọn Ìtọ́ka sí

àtúnṣe
  1. "AYO BAMGBOSE AT 80  : Nigerian Latest News Papers News Online". www.nigerianbestforum.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2017-02-06.