Ayọ̀ Bámgbóṣé
(Àtúnjúwe láti Ayo Bamgbose)
Ayọ̀ríndé Bámgbóṣé (ojoibi ọjọ́ 27 oṣù Kíní, ọdún 1932) jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n onímọ̀ ẹ̀dá èdè, tí ó sì tún jẹ́ ẹni àkọ́kọ́ tí ó gba oyò ọ̀jọ̀gbọ́n àkọ́kọ́ nínú ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ẹ̀dá èdè ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó ti ṣiṣẹ́ ribi ribi nínú ẹ̀kọ́ ìmọ̀ ẹ̀dá èdè, tí ó sì ti di ìlú mọ̀ọ́ká àti gbajú-gbajà láàrin àwọn akẹgbẹ́ rẹ̀ lágbo ìmọ̀ ẹ̀dá èdè.[1]
Ayo Bamgbose | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Ayọ̀rìndé Bámgbóṣé 27 Oṣù Kínní 1932 (age 86) Odopotu, Ijebu Ode, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University College London, University of Edinburgh |
Iṣẹ́ | Linguist, Professor, Scholar |
Ọmọ ìlú | Odopotu |
Àwọn Ìtọ́ka sí
àtúnṣe- ↑ "AYO BAMGBOSE AT 80 : Nigerian Latest News Papers News Online". www.nigerianbestforum.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2017-02-06.