Ayra Starr
Oyinkansola Sarah Aderibigbe (tí wọ́n bí ní ọjọ́ ẹrìnlá2oṣù kẹfà ọdún 002), tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ sì ń jẹ́ Ayra Starr, jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n bí ní orílẹ̀-èdè Benin. Ó jẹ́ olórin tí ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ nípa ṣíṣe àkọtúnkọ àwọn orin olórin lórí ẹ̀rọ-ayélujára, kí ó ṣe àgbéjáde orin tirẹ̀ gan-an gan. Orin rẹ̀ yìí ló pe àkíyèsi Don Jazzy, tó mu wọ ẹgbẹ́ orin tirẹ̀ tó ń jẹ́ Mavin Records.[1]
Ayra Starr | |
---|---|
Ayra Starr ní ọdún 2023 | |
Ọjọ́ìbí | Oyinkansola Sarah Aderibigbe 14 Oṣù Kẹfà 2002 Cotonou, Benin |
Orúkọ míràn | Celestial Being |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Les Cours Sonou, University |
Iṣẹ́ | Singer • Songwriter |
Ìgbà iṣẹ́ | 2018–present |
Musical career | |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Lagos, Nigeria |
Irú orin | |
Instruments | Vocals |
Labels | Mavin |
Associated acts |
|
Website | ayrastarr.com |
Àwon ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Don Jazzy activates Ayra Starr". This Day Live. 30 January 2021. Archived from the original on 28 September 2022. Retrieved 6 April 2021. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)