Michael Babatunde Olátúnjí

(Àtúnjúwe láti Bàbátúndé Ọlátúnjí)

Michael Babatunde Olatunji (April 7, 1927 – April 6, 2003) oje onílù Nàìjíríà, olukọni, alapon nínú awujọ, ati Olorin .[1]

Babatunde Olatunji
Orúkọ àbísọMichael Babatunde Olatunji
Ọjọ́ìbí(1927-04-07)Oṣù Kẹrin 7, 1927
Ajido, Lagos State, British Nigeria
AláìsíApril 6, 2003(2003-04-06) (ọmọ ọdún 75)
Salinas, California
Irú orinYoruba music, Apala
InstrumentsDrums, percussion, djembe
Years active1959–2003
LabelsColumbia, CBS, Narada, Virgin, EMI, Chesky
Websiteolatunjimusic.com
Babatunde Olatunji, second from right, at the Tal Vadya Utsav International Drums & Percussion Festival, Siri Fort Auditorium, New Delhi, 1985

Kutukutu ayé rẹ àtúnṣe

Olatunji jẹ ọmọ bíbí ìlú Ajido, ni èbá Badagry, Lagos State, ni guusu iwọ-oorun Nigeria. ọkàn lára Ogu people, a ṣe àfihàn Olatunji sí orin ìbílẹ̀ ní áfríkà ni tete ọjọ ori. Orúkọ rẹ , Bàbátúndé, tunmọ sí 'baba tí dé', nítorí a bi lẹhin oṣù Méjì tí bàbá rẹ̀ kú, eni Ogu (Egun) ọkunrin, Zannu kú, a sì pé Olatunji ni Bàbátúndé reincarnation. Baba re je apẹja father to fẹ jẹ olóyè chieftain, iya re sí je amọkoko ti ọ jẹ ọkan lára ọmọ Ogu people. Olatunji lati ma so ède Gun (Ogu/Egun) ati Yoruba language. Ìyá ìyá rẹ àti ìyá ìyá rẹ - ìyá àgbà je alufa ti Vodun ati ìgbàgbọ Ogu,wo má sìn Vodun, bí Kori, ti ọ jẹ oriṣa ti irọyin.[2][3] nitori ikú bàbá rẹ̀ of his father's , ni tete ọjọ ori a kò láti jẹ oyè gẹgẹ bí olóyè .

Ni ọmọ ọdún méjìlá, o mọ pé ohun o fe di olóyè. O ka ìwé Reader's Digest ìwé ìròyìn nípa Rotary International Foundation's scholarship program, ti ọ sí kó ìdánwò rẹ . A gbà wọlé ọ lọ sí ilé ìwé gíga United States of America ni ọdún 1950.

Èkó àtúnṣe

Olatunji gbà Ebun ìwé o fẹ ni ọdún 1950 o sí ka ìwé Morehouse College ni Atlanta, Georgia, níbití o ni èròngbà, sùgbón kó korin Morehouse College Glee Club. Olatunji je ọrẹ gidigidi sí oludari Glee Club Dr. Wendell P. Whalum o so'wopo láti dá egbé akọrin choir's repertoire, "Betelehemu", orin keresimesi Naijiria . Lẹyìn tí ọ jade ni ile iwe Morehouse, o tẹsiwaju sí New York University láti kà nípa public administration. Níbi tí ọ ti bẹrẹ, egbé onílù kékeré láti má pa owó bi ọ ṣe tẹsiwaju ninu iwe re .[4]

  1. "The Nigerian drummer who set the beat for US civil rights". BBC News. 2020-09-01. Retrieved 2020-09-05. 
  2. Olatunji, Babatunde; Atkinson, Robert (2005). The Beat of My Drum: An Autobiography. ISBN 9781592133543. https://books.google.com/books?id=U6xiXqGm49IC&q=akinsola+akiwowo&pg=PA6. 
  3. Martin, Andrew R.; Matthew Mihalka Ph, D. (September 30, 2020). Music around the World: A Global Encyclopedia [3 volumes]: A Global Encyclopedia. ISBN 9781610694995. https://books.google.com/books?id=wvb2DwAAQBAJ&q=zannu+olatunji&pg=PA625. 
  4. "Babatunde Olatunji 1927 – 2003". African Music Encyclopedia. May 2003. Archived from the original on June 5, 2011. Retrieved June 6, 2011.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)