Bálíníìsì

Bátíníìsì

Balinese
Basa Bali
Sísọ níBali, Nusa Penida, Lombok and Java, Indonesia
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀3.9 million (títí di 2001)
Èdè ìbátan
Sístẹ́mù ìkọLatin, Balinese
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-2ban
ISO 639-3ban

Balinese

Ọmọ ẹgbẹ́ ẹbí èdè Austronesian ni èdè yìí. Àwọn tí ó n sọ ọ́ fẹ́rẹ́ẹ̀ tó mílíọ̀nù mẹ́rin (3.8 million) ní erékùsù Báálì (Bali) ní In-indoníísíà (Indonesia). Àkọtọ́ Bálíníìsì àti ti Rómáànù (Balinese and Roman alphabet)ni wọ́n fi ń kọ èdè yìí sílẹ̀.

Bálíníìsì