Bálíníìsì
(Àtúnjúwe láti Balinese)
Balinese | |
---|---|
Basä Bali | |
Sísọ ní | Bali, Nusa Penida, Lombok and Java, Indonesia |
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀ | 3.9 million (títí di 2001[update]) |
Èdè ìbátan | |
Sístẹ́mù ìkọ | Latin, Balinese |
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè | |
ISO 639-2 | ban |
ISO 639-3 | ban |
Ọmọ ẹgbẹ́ ẹbí èdè Austronesian ni èdè yìí. Àwọn tí ó n sọ ọ́ fẹ́rẹ́ẹ̀ tó mílíọ̀nù mẹ́rin (3.8 million) ní erékùsù Báálì (Bali) ní In-indoníísíà (Indonesia). Àkọtọ́ Bálíníìsì àti ti Rómáànù (Balinese and Roman alphabet)ni wọ́n fi ń kọ èdè yìí sílẹ̀.