Bídèmí Kòsọ́kọ́
(Àtúnjúwe láti Bídèmí kòsọ́kọ́)
Bídèmí Kòsọ́kọ́ tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kọ̀kàndínlógún oṣù kẹwàá ọdún 1988 (21st October 1988)[1] jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Èkó, lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ọmọ gbajúgbajà òṣèré sinimá àgbéléwò, ọmọba Jídé Kòsọ́kọ́. Ẹbí wọn ní à bá má pè ní ẹbí sinimá àgbéléwò lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà, nítorí yàtọ̀ sí bàbá rẹ̀, ẹ̀gbọ́n rẹ̀ Ṣọlá Kòsọ́kọ́ àti ìyàwó bàbá rẹ̀, olóògbé Henrietta Kòsọ́kọ́ náà jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré sinimá àgbéléwò. [2] [3]
Bídèmí Kòsọ́kọ́ | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Ọjọ́ kọ̀kàndínlógún oṣù kẹwàá ọdún 1988 |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iṣẹ́ | òṣèré |
Àwọn olùbátan | Sola Kòsókó |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Charming Bidemi Kosoko Clocks ‘21’". THISDAYLIVE. 2018-10-27. Retrieved 2020-02-22.
- ↑ Godgrace (2019-02-08). "Bidemi Kosoko Biography, Husband, Age, Family, Movies and News". Nigeria's Coverage - Super Nigeria. Archived from the original on 2020-02-22. Retrieved 2020-02-22.
- ↑ "Bidemi Kosoko Biography - Profile - History - Wiki". 360dopes. 2018-08-07. Retrieved 2020-02-22.