Bọ́lá Ọdẹlékè
Bọ́lá Ọdẹlékè tí wọ́n bí lọ́dún 1850 jẹ́ òjíṣẹ́ Ọlọ́run, Ajíyìnrere Nàìjíríà àti Bíṣọ́ọ̀bù obìnrin àkọ́kọ́ ní Áfíríkà. Òun ni olùdásílẹ̀ ìjọ Power Pentecostal Church.[1][2]
Bọ́lá Ọdẹlékè | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Ọdún 1950 Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní Nàìjíríà |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Ọmọ Nàìjíríà |
Iṣẹ́ | Evangelist |
Ìgbà iṣẹ́ | 1977–present |
Ìgbà èwe rẹ̀
àtúnṣeỌdẹlékè jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Ìbàdàn, ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[3] Ó kàwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ àti ipele kejì ní Iléṣà ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, ìlú màmá tó bí i lọ́mọ.[4] Ó di onígbàgbọ́ ọmọlẹ́yìn Jésù lọ́dún 1970,ṣùgbọ́n ọdún 1974 ló bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ìyìnréré, tí ó sìn ṣe àjọyọ̀ ogójì ọdún tí ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ Ọlọ́run lọ́dún 2014.[5] Ó gboyè Bíṣọ́ọ̀bù lọ́dún 1995,òun sìn ní Bíṣọ́ọ̀bù obìnrin àkọ́kọ́ ní ilẹ̀ Áfíríkà.[6]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "A woman shouldn't be a sex object—Bola Odeleke". Vanguard News. Retrieved 28 February 2015.
- ↑ "Bling Bling Bishop, Bola Odeleke Pursues Tenants With OPC - Global News". globalnewsnig.com. Archived from the original on 27 February 2015. Retrieved 28 February 2015.
- ↑ Paul Ukpabio. "My regret: ….not believing God as much as I ought to". thenationonlineng.net. Retrieved 28 February 2015.
- ↑ "Now, I tell widows to mourn their husbands very well –Evangelist Bola Odeleke". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 10 March 2015. Retrieved 28 February 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ KAYODE ALFRED. "Bishop Bola Odeleke in the news". thenationonlineng.net. Retrieved 28 February 2015.
- ↑ "Bishop Bola Odeleke: My experience with men - churchtimesnigeria.org". churchtimesnigeria.org. Archived from the original on 27 February 2015. Retrieved 28 February 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)