Ìṣí ojúewé ètò àkọ́kọ́

Ìbàdàn

olúìlú ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní Nàìjíríà

Ìbàdàn jẹ́ ilú Nàìjíríà tí ó tó bí jùlo ni apá ìwọ̀òrùn Afríkà, bé ni ó sí jé olúìlú ìjoba ìpínlè Oyo. Ìbàdàn jé ilú àwon jagunjagun. Ìtumọ̀ orúkọ Ibàdàn ni ẹ̀bá ọ̀dàn (Near Savannah).

Ìbàdàn
Ìbàdàn pẹ̀lú Cocoa House ní ọ̀ọ́kán
Ìbàdàn pẹ̀lú Cocoa House ní ọ̀ọ́kán
Ìnagijẹ: Ile Oluyole
Ìbàdàn is located in Nigeria
Ìbàdàn
Ìbàdàn
Ibùdó ní Naijiria
Coordinates: 7°23′47″N 3°55′0″E / 7.39639°N 3.916667°E / 7.39639; 3.916667Àwọn Akóìjánupọ̀: 7°23′47″N 3°55′0″E / 7.39639°N 3.916667°E / 7.39639; 3.916667
Orílẹ̀-èdè  Naijiria
Ìpínlẹ̀ Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́
Ìjọba
 • Gomina Abiola Ajimobi
 • Alaga, Ariwa Ademola Kamil Omotoso
 • Alaga, Ariwa-Ila Oorun Olugbenga Ayinde Adewusi
 • Alaga, Ariwa-Iwo Oorun Aderemi Ayodele
 • Alaga, Guusu-Ila Oorun Abiodun Bolarinwa Adedoja
Ìtóbi
 • Total 1,190 sq mi (3,080 km2)
Agbéìlú (2005)
 • Total 2,550,593
 • Density 2,140/sq mi (828/km2)
 • Metro density 600/sq mi (250/km2)
 • Awon eya eniyan Yoruba
Time zone WAT (UTC+1)
Website http://www.oyostate.gov.ng/

Ìbàdàn bùdó sí apa gùùsu-ìwòorùn Nàìjíríà, 128 km sínú láti aríwáìlàorùǹ ìlú Èkó àti 530 km láti gúúsùìwọ̀orùn Abuja, olú-ìlú àpapò, bẹ́ẹ̀ sìni ó jé ibi ìgúnlẹ̀ pàtàkì láàrín agbèègbè ẹ̀bá òkun àti àwọn ibi tí wọ́n wà ní àríwá Nàìjíríà. Ibadan ti je gbongan ijoba fun Agbegbe Apaiwoorun atijo lati igba ijoba amusin Britani, be sini apa die ogiri bode to da abo bo ilu na si wa titi doni. Awon alabugbe to poju ni be ni awon omo Yoruba ati opo eniyan lati apa Naijiria yioku.

ÌtànÀtúnṣe

Ibadan je didasile ni odun 1829 nitori awon rogbodiyan to unsele ni Ilẹ̀ Yorùbá nigba na. Asiko yi ni awon ilu ti won se pataki ni ile Yoruba nigba na bi Ọ̀yọ́ ilé, Ìjàyè ati Òwu je piparun, ti awon ilu tuntun bi Abeokuta, Oyo atiba ati Ibadan dide lati dipo won. Gege bi awon onitan se so Lagelu, nigba na to je Jagun ilu Ife lo da Ibadan sile gege bi àgọ́ fun awon jagunjagun ti won unbo lati Oyo, Ife ati Ijebu.[1]

Jẹ́ọ́gráfìÀtúnṣe

Ojúọjọ́Àtúnṣe

Dátà ojúọjọ́ fún Ibadan
Osù Jan Feb Mar Apr May Jun Jul Aug Sep Oct Nov Dec Ọdún
Iye tógajùlọ °C (°F) 37.2
(99)
38.9
(102)
38.3
(100.9)
37.2
(99)
35.0
(95)
33.3
(91.9)
31.7
(89.1)
31.7
(89.1)
35.6
(96.1)
33.3
(91.9)
33.9
(93)
35.6
(96.1)
38.9
(102)
Iye àmúpín tógajùlọ °C (°F) 32.3
(90.1)
34.0
(93.2)
33.5
(92.3)
32.3
(90.1)
31.2
(88.2)
29.6
(85.3)
27.8
(82)
27.2
(81)
28.5
(83.3)
29.7
(85.5)
31.3
(88.3)
31.9
(89.4)
30.8
(87.4)
Iye àmúpín ojojúmọ́ °C (°F) 25.7
(78.3)
26.9
(80.4)
26.9
(80.4)
26.3
(79.3)
25.6
(78.1)
25.1
(77.2)
23.6
(74.5)
23.1
(73.6)
23.9
(75)
24.3
(75.7)
25.6
(78.1)
25.5
(77.9)
25.2
(77.4)
Iye àmúpín tókéréjùlọ °C (°F) 20.9
(69.6)
21.9
(71.4)
22.5
(72.5)
22.0
(71.6)
21.7
(71.1)
21.6
(70.9)
21.2
(70.2)
20.7
(69.3)
21.8
(71.2)
21.7
(71.1)
21.6
(70.9)
20.7
(69.3)
21.5
(70.7)
Iye tókéréjùlọ °C (°F) 10.0
(50)
11.1
(52)
15.0
(59)
18.3
(64.9)
17.8
(64)
17.8
(64)
16.1
(61)
15.6
(60.1)
17.2
(63)
17.8
(64)
15.6
(60.1)
11.1
(52)
10.0
(50)
Iye àmúpín ìrọ̀jò mm (inches) 10
(0.39)
25
(0.98)
91
(3.58)
135
(5.31)
152
(5.98)
188
(7.4)
155
(6.1)
86
(3.39)
175
(6.89)
160
(6.3)
46
(1.81)
10
(0.39)
1,233
(48.54)
Iye àmúpín àwọn ọjọ́ òjò (≥ 0.3 mm) 1 3 7 9 14 17 15 13 18 18 7 1 123
Iye àmúpín ìrì-omi (%) 76 73 77 82 85 87 89 88 88 87 83 79 83
Iye àmúpín wákàtí ìràn òrùn lósooòsù 198.4 197.8 186.0 180.0 195.3 147.0 86.8 65.1 93.0 164.3 207.0 220.1 1,940.8
Iye àmúpín wákàtí ìràn òrùn lójoojúmọ́ 6.4 7.0 6.0 6.0 6.3 4.9 2.8 2.1 3.1 5.3 6.9 7.1 5.3
Source: Deutscher Wetterdienst[2]

ÌjọbaÀtúnṣe

ÒkòwòÀtúnṣe

Àwọn ìtọ́kasíÀtúnṣe

  1. "Ibadan History" (in en-US). Litcaf. 2016-02-12. https://litcaf.com/ibadan-history/. 
  2. "Klimatafel von Ibadan / Nigeria" (PDF). Baseline climate means (1961-1990) from stations all over the world (in German). Deutscher Wetterdienst. Retrieved 14 July 2016.