Bọ́lá Agbájé tí wọ́n bí lọ́dún 1981 [1] jẹ́ gbajúmọ̀ oǹkọ̀wé eré-oníṣe ọmọ Nàìjíríà.[2] Ìlú London ni àwọn òbí rẹ̀ tí wọ́n jẹ́ ọmọ Nàìjíríà bí i sí [3]

Iṣẹ́ rẹ̀

àtúnṣe

eré-oníṣe àkọ́kọ́ tí Agbájé kọ ni Gone Too Far!, wọ́n gbé e jáde ní Royal Court TheatreLondon, níbi tí ó ti gba àmìn-ẹ̀yẹ Laurence Olivierfún àrà ọ̀tọ̀ iṣẹ́ tíátà .[4][2] Wọ́n tún ṣe àtúngbejáde rẹ̀ ní ráńpẹ́ ní' Albany Theatre àti Hackney Empire.[4]

Agbájé náà ló tún kọ eré-oníṣe, The Burial.[5]

Lọ́dún 2018, wọ́n Agbájé gẹ́gẹ́ bí ọkàn nínú àwọn ogójì, tí ọjọ́ orí wọn kò ju ogójì lọ, tí wọ́n yàn ní Royal Society of Literature láti dẹ́kun àlàfo ìtàn.[6]

Ìgbésí-ayé ara rẹ̀

àtúnṣe

Agbájé sọ pé òun gbàgbọ́ nínú Ọlọ́run ṣùgbọ́n òun kò ní ìgbàgbọ́ nínú ẹ̀sìn ọmọ-lẹ́yìn Jésù tàbí Mùsùlùmí.[2] Her brother served time in prison.[2]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Bola Agbaje". ZODML. 2014-06-30. Retrieved 2020-11-07. 
  2. 2.0 2.1 2.2 2.3 "The Write Stuff: Stenham & Other Courtiers", What's On Stage, 28 April 2008.
  3. "BPA". Agbaje; Bola. Retrieved 2020-11-07. 
  4. 4.0 4.1 "Gone Too Far! on Tour", Royal Court, 2008.
  5. Bayes, Honour (7 May 2013), "The Burial" (review), Time Out.
  6. Flood, Alison (2018-06-28). "Royal Society of Literature admits 40 new fellows to address historical biases". The Guardian (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2018-07-03.