Bọ́lájí Akínyẹmí

Akínwándé Bọ́lájí Akínyẹmí tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrin oṣù kìíní ọdún 1942 (January 4, 1942) jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n onímọ̀ sáyẹ́nsì, olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà[1] to di Alakoso Oro Okere Naijiria lati 1985[2] titi de opin 1987.[3] Ohun ni Alaga National Think Tank.[4]

Bolaji Akinyemi
External Affairs Minister of Nigeria
In office
1985–1987
ÀàrẹIbrahim Babangida
AsíwájúIbrahim Gambari
Arọ́pòIke Nwachukwu
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíJanuary 4, 1942
Ilesa, Osun State
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
(Àwọn) olólùfẹ́Rowena Akinyemi
Àwọn ọmọAtinuke Akinyemi, Tosin Akinyemi, Tolu Akinyemi, Benjamin Akinyemi
ProfessionProfessor of political science
Websitewww.profbolajiakinyemi.com



Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. Shaw, Timothy M.; Julius Omozuanvbo Ihonvbere. Illusions of Power: Nigeria in Transition. Africa World Press. p. 190. ISBN 0865436428. 
  2. Oloyede, Dokun (2002-01-06). "Bolaji Akinyemi, the Seagull, at 60". Thisday online (Leaders & Company). Archived from the original on 2007-12-08. https://web.archive.org/web/20071208041700/http://www.thisdayonline.com/archive/2002/01/06/20020106tri01.html. Retrieved 2007-10-27. 
  3. Shaw, 127.
  4. "National Think Tank pledges support for Omehia". The Tide Online (Rivers State Newspaper Corporation). 2007-10-10. http://www.thetidenews.com/article.aspx?qrDate=10/10/2007&qrTitle=National%20Think%20Tank%20pledges%20support%20for%20Omehia&qrColumn=FRONT%20PAGE. Retrieved 2007-10-27.