Baálẹ̀ ni orúko oyè tí Yorùbá n pè olórí abúlé tàbí agbègbè kan. Bakanna Baálẹ̀ (mayor) ni olórí ìjoba ìlú tàbí ìjọba ìbílẹ̀ kan. Àwọn ọmọ-ìlú ni wón máa n jẹ oyè Baálẹ̀. Àwọn báálẹ̀ máa n jẹ́ aṣojú Ọba aládé ní àwọn ìlú kéréjekéréje tí ó bá wà lábé àkóso irú ọba bẹ́ẹ̀. Oba alade ni won maa n fi Baale joye nile Yoruba[1]

Baálẹ̀

A ní ipele mẹ́ta nínu ìjọba ilé Yorùbá. Èyí ni ipò ọba, àwọn ìjòyè gíga rẹ̀ àti àwọn Báálẹ̀.[2]