Babátúndé Fowler
Ọ̀mọ̀wé Babátúndé Fowler (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ Kejìlá oṣù kẹjọ ọdún 1956) jẹ́ akọ́ṣẹ́mọṣẹ́ ètò nípa kòkárí owó-orí àti òṣìṣẹ́ ìjọba. Ó ti fìgbà kan jẹ́ Alága yányán fún ilé iṣẹ́ ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó (Lagos State Internal Revenue Service, LIRS) àti ti ìjọba àpapọ̀ (Federal Inland Revenue Service, FIRS) tí ó ń ṣe kòkárí owó-orí gbígbà. Lọ́jọ́ kẹsàn-án oṣù Kejìlá ọdún 2019 ní Ààrẹ Muhammadu Buhari yan Ọ̀gbẹ́ni Muhammad Nami sí ipò náà nígbà tí sáà Fowler parí.[1] [2] [3] [4]
Babatunde Fowler | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 12 Oṣù Kẹjọ 1956 Lagos, Lagos State, Nigeria |
Ibùgbé | Lagos, Lagos State, Nigeria |
Iṣẹ́ | Tax Administrator |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Laying the Groundwork". The Business Year. Archived from the original on 2019-12-10. Retrieved 2019-12-10.
- ↑ "Profile Of Babatunde Fowler, The New FIRS Chairman". LATEST NIGERIAN NEWS BREAKING HEADLINES NEWSPAPERS. 2015-08-21. Retrieved 2019-12-10.
- ↑ "FIRS". FIRS. 2019-12-10. Retrieved 2019-12-10.
- ↑ "UPDATED: Fowler out as Buhari appoints new chairman for FIRS". Premium Times Nigeria. 2019-12-09. Retrieved 2019-12-10.