Babatunde Ayi Olatundun
Babatunde Ayi Olatundun jẹ́ alábòójútó àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó ń ṣoju ẹkùn ìdìbò àríwá-ìwọ̀ oòrùn Ilorin, ní ìjọba ìbílẹ̀ Ìwọ̀ Oòrùn Ilorin ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin kẹwàá ni ilé ìgbìmò aṣòfin ni ipinlẹ Kwara . [1] [2] [3]
Babatunde Ayi Olatundun | |
---|---|
Member of the Kwara State House of Assembly | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 18 March 2023 | |
Member of the Kwara State House of Assembly from Ilorin, Ilorin West Local Government | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 18 March 2023 | |
Constituency | Ilorin North-West Constituency |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 12 Oṣù Kẹjọ 1961 Ilorin, Ilorin West Local Government Kwara State Nigeria |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressive Congress |
Alma mater | |
Occupation |
|
Igbesi aye ibẹrẹ ati ẹkọ
àtúnṣeWon bi Babatunde ni ojo kejila osu kẹjọ ọdún 1961 ni ìlú Ilorin, ni ijoba ibile Ilorin West ni ipinle Kwara Nigeria o lo si ile iwe giga Oyun Baptist High School, Ijagbo ni ijoba ibile Oyun ni ipinle Kwara Nigeria o si gba iwe eri ile iwe West African School ni odun 1981.
Iṣẹ-ṣiṣe
àtúnṣeLaarin ọdun 1989 si 1994 o ṣiṣẹ gẹgẹ bi Alákóso Ìṣàkóso ni Kwara State Broadcasting Services (Radio Kwara) ati awọn ile-iṣẹ aladani miiran ko too darapọ mọ iṣelu ni ọdun 2014 nibiti wọn ti yan lati ṣiṣẹ gẹgẹbi oludari obìnrin ìpínlè ti People's Democratic Party mejeeji ati Buhari Support Organisation titi di ọdun 2022 leralera ṣaaju idibo rẹ gẹgẹ bi ọmọ ile-igbimọ aṣofin ipinlẹ ti o ṣoju ẹkun idibo North-West Ilorin ni ile igbimọ aṣofin ipinlẹ Kwara ni ìdìbò Gbogbogbòò 2023. [4]