Babatunde Elegbede
Olóṣèlú
Muftau Adégòkè Babátúndé Elégbèdé (c. 1939 - 19 June 1994) òun náà tún ni Túnde Elégbèdé. Ó jẹ́ ọ̀gá ológun ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Cross River nígbà kan rí.
Muftau Adegoke Babatunde Elegbede | |
---|---|
Governor of Cross River State | |
In office 28 July 1978 – 30 September 1979 | |
Asíwájú | Paul Omu |
Arọ́pò | Clement Isong |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | c. 1939 |
Aláìsí | 19 June 1994 |