Àwọn èdè Balto-Sílàfù

(Àtúnjúwe láti Balto-Slavic)

Awon ede Balto-Slavic Ẹgbẹ́ àwọn èdè tí wọ́n ní Baltic ati Slavic ni àwọn wọ̀nyí tí wọ́n wá ń pe àwọn méjèèjì papọ̀ ní Balto-Slavic. Ọmọ ẹgbẹ́ ni àwọn èdè wọ̀nyí jẹ́ fún àwọn ẹ̀yà èdè (branch) tí a ń pè ní Indo-European (In-indo-Yùrópíànù). Àwọn tí ó ń sọ Baluto-Sìláfíìkì yìí tí mílíọ̀nù lọ́nà ọ̀ọ́dúnrún ènìyàn (300 million people). Eléyìí tí ó ju ìlàjì lọ nínú àwọn ènìyàn wọ̀nyí ni ó ń sọ èdè Rọ́síà (Russian)

Balto-Slavic
Ìpínká
ìyaoríilẹ̀:
Eastern and Northern Europe
Ìyàsọ́tọ̀:Indo-European
  • Balto-Slavic
Àwọn ìpín-abẹ́:

Èdè àìyedè díẹ̀ wà lórí pé bíyá ibi kan náà ni gbogbo àwọn èdè yìí ti ṣẹ̀ tàbí pé nítorí pé wọ́n jọ wà pọ̀ tí wọ́n sì jọ ń ṣe pọ̀ ló jẹ́ kí ìjọra wà láàrin wọn.