Bamidele Aturu
Bamidele Aturu (Oṣù Kẹ̀wá Ọjọ́ 16, Ọdún 1964 – Oṣù Keje Ọjọ́ 9, Ọdún n 2014)[1][2][3] jẹ́ Agbẹjọ́rọ̀ orílẹ́èdè Nàìjíríà àti ajafẹtọ ọmọ ènìyàn. [4][5][6]
Bamidele Aturu | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Ogbagi, Ondo State, Nigeria | Oṣù Kẹ̀wá 16, 1964
Aláìsí | July 9, 2014 | (ọmọ ọdún 49)
Iléẹ̀kọ́ gíga | Obafemi Awolowo University |
Iṣẹ́ | Nigerian Lawyer and human rights activist. |
Ìgbésí ayé àti ìṣẹ́
àtúnṣeỌjọ́ kẹrin dínlógún oṣù kẹwàá ọdún n 1964 ní wọ́n bí Aturu ní Ìpínlẹ̀ Ogbagi Òndó ní Nàìjíríà sí ìdílé Aturu. Ó kọ ẹkọ fisiksi ní Adeyemi College of Education ní Ìpínlẹ̀ e Òndó , Nigeria. Ò tẹsiwaju sì ile ẹkọ gíga ga Obafemi Awolowo ní ọdún 1989, láti i kò ọ ẹkọ nípa òfin àti parí ní LL. B ní ọdún 1994. Lẹhin náà ò lọ sí iile-iwe òfin n Nàìjíríà a àti pé wọn pé sì Bá ní ọdún un 1995. Ó gbà òye òye nípa òfin (LL.M) lati ilé ẹ̀kọ́ giga, University of Lagos ní ọdún n 1996. [7]
Ní 2010, ó mú Ìgbìmò ọ fún Ẹkọ Òfin lọ sì ilé ẹjọ́ , ó béèrè fún idínkù nínú àwọn owó tí ó mú kí àwọn ànfàní tí àwọn ọmọ ilẹ̀ ìwé òfin tí kò ní i aláìní láti lọ sí Ilé ìwé Òfin . Bákannáà ní 2012, ó kọwe si Gómìnà tí i Central Bank of Nigeria tẹ́lẹ̀ , Sanusi Lamido Sanusi, béèrè lọwọ rẹ̀ láti ṣafihan owó oṣù rẹ̀ , àwọn iyọọda àti àwọn ẹtọ mìíràn.[8][9][10] O pinnu láti ṣé aṣojú àwọn ẹnì-kọọkan àti àwọn ẹgbẹ́ tí à ni lára. [11] Òun ní okọwe àwọn ìwé òfin púpọ̀, pẹ̀lú A Handbook of Nigerian Labor Laws, Nigerian Labor Laws, Elections and the Law.[12] [13] Ó kọ yíyàn rẹ̀, gẹgẹbi aṣojú tí àwùjọ aráàlú, ní Àpéjọ Orilẹ̀ èdè lórí ìpìlẹ̀ pé àpéjọ náà, kò lè pàdé àwọn ìrètí àwọn ọmọ Nàìjíríà.[14] Ó kú ní ìlú Èkó ní Oṣù Keje Ọjọ́ 9, Ọdún 2014, tí wọn sì sìn sì ìlú rẹ, Ogbagi Àkókò, Ìpínlẹ̀ Òndó ní Nàìjíríà. O ní ọmọ méjì.[15][16][17][18]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "For Bamidele Aturu, 1964-2014". Vanguard News.
- ↑ "Activist lawyer, Bamidele Aturu dies @ 49". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2014-07-09. Retrieved 2022-04-07.
- ↑ "Tears flow as late human rights lawyer, Bamidele Aturu, begins home journey | Premium Times Nigeria" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2014-07-23. Retrieved 2022-04-07.
- ↑ "Human rights lawyer, Bamidele Aturu buried in Ondo amid tears, tributes". DailyPost Nigeria.
- ↑ "Bamidele Aturu - P.M. NEWS Nigeria". pmnewsnigeria.com.
- ↑ "Bamidele Francis Aturu 1964-2014". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2014-08-08. Retrieved 2022-04-07.
- ↑ "Bamidele Aturu: A short but eventful life". tribune.com.ng. Archived from the original on 2014-11-09. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Aturu dares Sanusi Lamido to disclose his salary, allowances". DailyPost Nigeria.
- ↑ "Sanusi's suspension: Jonathan erred — Aturu - Vanguard News". Vanguard News.
- ↑ "Suspension of Sanusi Lamido illegal, says Bamidele Aturu - P.M. NEWS Nigeria". pmnewsnigeria.com.
- ↑ Empty citation (help)
- ↑ Human Rights at Work. https://books.google.com/books?id=rA_cBAAAQBAJ&dq=A+Handbook+of+Nigerian+Labour+Laws+by+Bamidele+Aturu&pg=PA240.
- ↑ Nigerian Labour Laws. https://books.google.com/books?id=4DIxtwAACAAJ.
- ↑ "Nigerians Mourn Aturu". newshunt.com. 11 July 2014. Archived from the original on 2 November 2014. Retrieved 1 November 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Bamidele Aturu: A Tribute To An Uncommon Fighter By Denja Yaqub". Sahara Reporters.
- ↑ "Tofa talks tough on national dialogue". Daily Independent, Nigerian Newspaper.
- ↑ "Bamidele Aturu - INFORMATION NIGERIA". informationng.com.
- ↑ "Prominent Human Rights Activist Bamidele Aturu Dead At 49". Sahara Reporters.