Bamike Olawunmi

Òṣèrébìnrin ti ilẹ̀ Nàìjíríà

Bamike Olawunmi,Yo-Bamike Olawunmi.ogg Listen tí ọ̀pọ̀ ènìyàn mọ̀ sí Bambam jẹ́ òṣèrébìnrin, ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Òun ni ìyàwó òṣèrẹ́kùnrin kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Tope Adenibuyan. Ó gbajúmọ̀ fún ìkópa rẹ̀ nínú àwọn fíìmù bí i Inspector K, Backup Wife àti Foreigner's God.[1][2][3][4]

Bamike Olawunmi
Ọjọ́ìbíLagos, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Orúkọ mírànBambam
Ẹ̀kọ́Nigerian Navy Primary School, Apapa,

La Folie St. James, Paris, France The Bells University, Ota,

The Royal Film Academy
Iléẹ̀kọ́ gígaBig Brother Naija
Iṣẹ́Actor
Gbajúmọ̀ fúnForeigner's God
Olólùfẹ́Tope Adenibuyan

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Bambam ní àkọ́bí nínú ìdílé kan tí ìyá jé nọ́ọ̀sì tó ti fẹ̀yìntí, tí bàbá sì jẹ́ òsìṣẹ́ ìjọba. Ó ti gbé pẹ̀lú bàbá rẹ̀ ní America, France àti United Kingdom nítorí iṣẹ́ bàbá náà.[5] Bambam gba ìwẹ́-ẹ̀rí ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ ní Nigerian Navy Primary School, Apapa. Ó sì gba ìwé-ẹ̀rí ẹ̀kọ́ tó tẹ̀le ní La Folie St. James, Paris, France, àti oyè B.A ní The Bells University, Ọ̀tà.[5]

Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí i òṣèré

àtúnṣe

Bambam bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ fíìmù ṣíṣe ní ọdún 2017 nígbà tí ó ṣì jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ ní Royal Arts Academy. Láti ìgbà náà ni ó ti ń kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù bí i Inspector K’, ‘Backup Wife àti Foreigner's God.[6][7][8][9]

Ìgbésí ayé ara ẹni

àtúnṣe

Bambam fẹ́ Tope Adenibuyan, èyí tí í ṣe akẹgbé rẹ̀ nínú ètò Big Brother Naija. Ìgbéyàwò ní ìlànà ìbílẹ̀ wáyé ní ọjọ́ keje oṣù kẹsàn-án ọdún 2019 ní Ìpínlẹ̀ Ògùn, wọ́n sì ṣe ìgbéyàwò ní ìlànà òyìnbó ní ìlú Dubai, UAE ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kọkànlá ọdún 2019. Bambam àti ọkọ rẹ̀ jìjọ ní ọmọ méjì.[10][11]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. CHRISTINE (9 February 2022). "BBNaija Stars Bam Bam, Teddy A Expecting Second Child Together". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 26 July 2022. 
  2. "Movie Fans Await Ifan Michael's 'Foreigner's God' – THISDAYLIVE". www.thisdaylive.com. Retrieved 26 July 2022. 
  3. Augoye, Jayne (16 November 2019). "BBNaija's Teddy A, Bam Bam wed in Dubai". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 26 July 2022. 
  4. Okonofua, Odion (3 March 2022). "'You reminded me of the people parents warned us to be wary of' - Bam Bam talks about meeting Teddy A for the 1st time". Pulse Nigeria. Retrieved 26 July 2022. 
  5. 5.0 5.1 "I was relieved when I got evicted from Big Brother Nigeria – Bamike Olawunmi (Bambam)". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 20 October 2018. Retrieved 26 July 2022. 
  6. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :02
  7. Falade, Tomi. "BamTeddy, Foreigner's God". 
  8. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :12
  9. Augoye, Jayne (2 May 2018). "#BBnaija: Teddy A, Bambam land Nollywood roles". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 26 July 2022. 
  10. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :22
  11. "BBnaija's Bam Bam Reveals Her Journey Through Pregnancy". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 27 May 2020. Retrieved 26 July 2022.