Banana Island Ghost
Banana Island Ghost (Òkú Erékùsù Ọ̀gẹ̀dẹ̀) jẹ fiimu ti a gbe jáde ni ọdún 2017. Olùkọ̀tàn àti oludari fiimu naa ni BB Sasore Olùdarí Àgbà fiimu naa ni Derin Adeyọkunnu ati Biọla Alabi. Àwon òṣèré tí o kó'pa ninu fiimu naa ni Ali Nuhu, Saheed Balogun, Tina Mba àti Bimbo Manuel.[1]
Banana Island Ghost | |
---|---|
Adarí | Biọla Alabi Derin Adeyọkunnu |
Òǹkọ̀wé | BB Sasore |
Àwọn òṣèré | Ali Nuhu Saheed Balogun Tina MBA Bimbo Manuel. |
Déètì àgbéjáde | 2017 |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Àwon tí o kó'pa nínú rẹ
àtúnṣe- Saheed Balogun
- Ali Nuhu
- Tina Mba
- Uche Jombo
- Bimbo Manuel
- Dorcas Shola Fapson
Àgbéka'lẹ̀ eré
àtúnṣeÌtẹ́wọ́gbà
àtúnṣeÀjọ tí o ńṣe àgbéyẹ̀wò fiimu ti a n pe ni Nollywood Reinvented fún fiimu yi ni àmì ìdá mọ́kàn-dín-lọ́gọ́ta nínú ọgọrun (59% rating). [2]