Banga Rice jẹ́ ọ̀kan lára àwọn iresi ní Nàìjíríà tí wón fi eyín àti ọbẹ̀ ẹ̀yìn se.[1][2][3] Àwọn ẹ̀yà Urhobo ní apa gúúsù Nàìjíríà ni wọ́n má ń sábà sè é. Banga túmọ̀ sí omi tí wọ́n ba yọ lára eyìn. Wọ́n ń pe ní iresi banga nítorí bí wọ́n bá ti fún omi jáde lara eyìn tán, wọ́n ó fi se iresi.

Banga rice
TypeRice
Place of originNigeria
Region or stateDelta
Created byUrhobo People
Main ingredientsPalm nut fruit, salt, water, white rice, other seasonings, meat, fish
Àdàkọ:Wikibooks-inline 

Àwọn ẹ̀yà urhobo[4] kì í fi èròjà bí; Taiko, Benetientien, tàbí Rogoje sí Banga Rice wọn[5] bí wọ́n se ń fi sí ọbẹ̀ Banga wọn.


Àwọn Ìtókasí

àtúnṣe
  1. "How To Prepare Banga Rice". Whatsdalatest (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-04-12. 
  2. Ndeche, Chidirim (October 24, 2017). "How To Make Banga Rice". The Guardian. Archived from the original on June 25, 2021. https://web.archive.org/web/20210625011454/https://guardian.ng/life/food/how-to-make-banga-rice/. 
  3. Yemi, Sissie (February 4, 2020). "How to Cook Banga Rice". YouTube. Archived from the original on 2020-02-04.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. "How to make Urhobo Banga rice bang". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-04-12. 
  5. "Banga Soup (Ofe Akwu)". All Nigerian Recipes (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-04-12.