Barney Simon
Barney Simon (ọjó kẹtàlá oṣù Ìgbé ọdún 1932 – si ọgbọn ọjó oṣù okundu ọdún 1995)[1] kí a má ṣe dà á pọ mọ́ Jacaranda FM radio DJ Barney Simon. Barney Simon jẹ́ òǹkọ̀wé ilẹ̀ South African àti olùdarí fíìmù. Ìlú Johannesburg ní SOuth Africa ni wọ́n bi sí, ibẹ̀ sì ni ó kú sí.[2]
Barney Simon | |
---|---|
Ọjọ́ ìbí | 13 Oṣù Kẹrin 1932 |
Ọjọ́ aláìsí | 30 June 1995 (aged 63) |
Iṣẹ́ | Playwright, director |
Èdè | English |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | South African |
Notable works | Woza Albert! |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
àtúnṣeSimon ṣe àwárí ìfẹ́ rè fún iṣẹ́ tíátà lásìkò tí ó ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Joan Littlewood ní London, ní ọdún 1950. Lẹ́yìn tó padà sí Johannesburg, ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí i òǹkọ̀wé fún ilé-iṣẹ́ ìpolówó-ọjà kan, lásìkò tó ń ṣịṣẹ́ olùdarí fún fíìmù. Ki o tó ṣí ọjà náà, o n ṣe eré ìtàgé nibi gbogbo ti ọ bá ti ni ore ọfẹ lati ṣe: in warehouses and shantytowns, storefronts and back yards, including Athol Fugard's The Blood Knot (1961). Simon spent a year (1969–70) in New York City, where he introduced South African plays to an American audience and edited the journal New American Review.
Àwọn ìwé àtẹ̀jáde rẹ̀
àtúnṣeÀṣààyàn erẹ́-oníṣe
àtúnṣe- Phiri (1972)
- Hey Listen (1973) is
- People (1973)
- People Too (1974)
- Storytime (1975)
- Cincinnati (1979)
- Cold Stone Jug (1980)[3]
- Call Me Woman (1980)
- Marico Moonshine and Manpower (1981)
- Woza Albert! (1981)
- Black Dog-Inj Mayama (1984)
- Born in the RSA (1985)[4]
- Outers (1985)
- Klaaglied vir Kous (1986)
- Inyanga - about Women in Africa (1989)
- Eden and Other Places (1989)
- Score me the Ages (1989)
- Starbrites (1990)
- Singing The Times (1992)
- Silent Movie (1993)
- The Lion and the Lamb (1993)
- The Suit (1994)
Àwọn ìtọkasí
àtúnṣe- ↑ Nadine Gordimer (3 July 1995). "Obituary: Barney Simon". The Independent. https://www.independent.co.uk/news/people/obituary-barney-simon-1589772.html.
- ↑ Mary Benson (3 July 1995). "Obituary; Barney Simon: For freedom of the heart and mind". The Guardian: p. 12.
- ↑ B. Simon; S. Gray; H. C. Bosman (1982), Cold Stone Jug, Cape Town: Human & Rousseau. ISBN 978-0-79811-309-0
- ↑ Barney Simon (1997), Born in the RSA: four workshopped plays, Johannesburg: Witwatersrand University Press. ISBN 978-1-86814-300-9