Bayo Adebowale
Bayo Adebowale (bí ni ọjọ́ kẹfà, Oṣù Òkudù, ọdún 1944), jẹ́ òǹkọ̀wé àròsọ, akéwì, Ọ̀jọ̀gbọ́n, lámèyító, alákòóso ìyára ìsọlọ́jọ ìwé àti ìkàwé àti olùdásílẹ̀ Ibùdó àṣà àti ìyára ìsọlọ́jọ̀ ìwé àti ìkàwé Àjogúnbá Adúláwò (African Heritage Library and Cultural Centre) ní Adéyípo, Ìbàdàn Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.
Bayo Adebowale |
---|
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀
àtúnṣeWọ́n bí i ni Oṣù Kẹfà, ọdún 1944, ni ìlú Ìbàdàn, olú-ìlú ipinle Ọ̀yọ́, apá ìwọ̀ oòrùn Nàìjíríà sínú ìdílé Àkàngbé Adébọ̀wálé, tí ó jẹ́ àgbẹ̀. Ilé ẹ̀kọ́ Secondary Modern School ló ti kẹ́kọ̀ọ́ níbi tí ó ti gba iwe ẹ̀rí West African School Certificate ní ọdún 1958 kí ó tó tẹ̀síwájú láti kẹ́kọ̀ọ́ sí i ní St. Peter's Teacher College níbi tí ó ti gba iwe ẹ̀rí Ìpele kẹtà (Grade III) nínú ètò ẹ̀kọ́ ni ọdún 1861. Ní ọdún 1961, ọdún yìí lánàá ni wọ́n gbà á wọlé sí Kọ́lẹ́jì Baptist ní Ẹdẹ fún ìwé ẹ̀rí Ìpele kejì Olùkọ́ ní ọdún 1971. Ó tún tẹ̀síwájú lọ sí Yunifásítì tí Ìbàdàn níbi tí ó ti gba Oyè ẹ̀ka Ajẹmọ́ṣẹ́ ọnà (Bachelor of Arts) nínú èdè Gẹ̀ẹ́sì ni ọdún 1974, ọdún yìí náàni ó lọ ṣe ìsìn ìlú gẹ́gẹ́ bí àgùníbarọ̀ ni ọdún 1975. Ọdún yìí ló darapọ̀ mọ́ Ajọ́ aráàlú tí ìwọ oòrùn Nàìjíríà (Western State Public Commission) gẹ́gẹ́ bí òṣìṣẹ́ ètò ẹ̀kọ́ kí ó tó wá di Olùkọ́ èdè Gẹ̀ẹ́sì ní Ibùdó káràkátà tí ìjọba Government Trade Centre, Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Lẹ́yìn ọdún mẹ́ta (1978). Ó gba oyè Master's ní Ède Gẹ̀ẹ́sì, ọdún yìí lánàá ló darapọ̀ mọ́ Kọ́lẹ́jì Ẹ̀kọ́sẹ́ àwọn olùkọ́ni tí Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ gẹ́gẹ́ bí Olùkọ́ tí wọ́n sí gbé e lọ sí Polytechnic tí Ìbàdàn níbi tí ó ti ga dé ipò igbákejì Olórí láàrin ọdún 1999 àti 2003 lẹ́yìn tí ó ti gba oyè onímọ̀ ìjìnlẹ̀ èrò - (Ph.D) nínú lítíréṣọ̀ àti Gẹ̀ẹ́sì ní Yunifásítì Ìlorin ní ọdún 1997.
Orúkọ rẹ̀
àtúnṣeIṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeIṣẹ́. Ó ti gbé ogúnlọ́gọ̀ ìwé jáde, àwọn ìtàn kéékèèké àti àwọn ìtàn àròsọ gẹ́gẹ́ bí ògbóǹtarìgì òǹkọ̀wé. Wọ́n fi Ìwé rẹ̀ àkọ́kọ́ "The Virgin", ṣe fíìmù Orílẹ̀èdè Nàìjíríà méjì. The Narrow Path, fíìmù Orílẹ̀èdè Nàìjíríà tí Tunde Kelani ṣe olótùú tí ó sì dárí rẹ̀ ní ọdún 2006, ṣe àfihàn Sola Asedeko, àti The White Handerkerchief. Òun ló kọ́ Lonely Days, Ìwé tí ó fojúsun àṣà ilẹ̀ Adúláwò. Ó kó ipa pàtàkì nínú lítíréṣọ̀ Ajẹmọ́ Adúláwò ní Gẹ̀ẹ́sì. Bákan náà ó kọ́ ìwé "Out of his Mind. Ní ọdún 1972, ìtàn rẹ̀ kékeré tí ó pè ní The River Goddess gba àmì ẹyẹ Western Festival of Arts Literary Competition. Bákan náà ní ọdún 1992, ewì rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ ń Perdition gba àmì ẹ̀yẹ Africa Prize nínú Index lórí ìdíje Censorship International Poetry ni Ìlú London. Wọ́n ti lo àwọn iṣẹ́ nínú iṣẹ́ ìwádìí bákan náà, wọ́n fi ń kẹ́kọ̀ọ́ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ Yunifásítì.
Àwọn itọ́ka sí
àtúnṣe"Artistic bells in a science world". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 2015-04-10.
"The man who grew larger than life". nigeria.gounna.com. Archived from the original on 10 April 2015. Retrieved 4 April 2015.
Latestnigeriannews. "Research: Expert seeks improved govt funding". Latest Nigerian News.
"BAYO ADEBOWALE:BIOGRAPHICAL SKETCH". AFRICAN LITERATURE:IN HONOUR OF AFRICAN WRITERS: 1. BAYO ADEBOWALE. 2009-02-09. Retrieved 2020-05-27.
"Welcome to Adeyipo Village - Nigeria Content Online". nigeriang.com.
Holger G. Ehling; Claus-Peter Holste-von Mutius, eds. (2001). No Condition Is Permanent: Nigerian Writing and the Struggle for Democracy. Rodopi. p. 189.
Adewale Oshodi. "How SYNW is promoting unknown young writers in Nigeria". tribune.com.ng. Archived from the original on 2015-04-10.
"Bearing Witness". google.co.uk.
"Bayo Adebowale's moving lines for African heroes". Punch Newspapers. 2017-04-06. Retrieved 2022-03-04.
"The Virgin". google.co.uk.
David Kerr; Jane Plastow, eds. (2011). Media and Performance. Boydell & Brewer. p. 30.
Lonely Days. Spectrum Books. 2006.
"Black African Literature in English, 1997-1999". google.co.uk.
"Thought with Pen: Book Review: Out of His Mind – Bayo Adebowale". Thought with Pen. 2015-09-12. Retrieved 2020-01-17.
"Archived copy" (PDF). Archived from the original (PDF) on 2015-04-10. Retrieved 2015-04-04
Ìtọ́kasí:
"Artistic bells in a science world". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 2015-04-10.
"The man who grew larger than life". nigeria.gounna.com. Archived from the original on 10 April 2015. Retrieved 4 April 2015.
Latestnigeriannews. "Research: Expert seeks improved govt funding". Latest Nigerian News.
"BAYO ADEBOWALE:BIOGRAPHICAL SKETCH". AFRICAN LITERATURE:IN HONOUR OF AFRICAN WRITERS: 1. BAYO ADEBOWALE. 2009-02-09. Retrieved 2020-05-27.
"Welcome to Adeyipo Village - Nigeria Content Online". nigeriang.com.
Holger G. Ehling; Claus-Peter Holste-von Mutius, eds. (2001). No Condition Is Permanent: Nigerian Writing and the Struggle for Democracy. Rodopi. p. 189.
Adewale Oshodi. "How SYNW is promoting unknown young writers in Nigeria". tribune.com.ng. Archived from the original on 2015-04-10.
"Bearing Witness". google.co.uk.
"Bayo Adebowale's moving lines for African heroes". Punch Newspapers. 2017-04-06. Retrieved 2022-03-04.
"The Virgin". google.co.uk.
David Kerr; Jane Plastow, eds. (2011). Media and Performance. Boydell & Brewer. p. 30.
Lonely Days. Spectrum Books. 2006.
"Black African Literature in English, 1997-1999". google.co.uk.
"Thought with Pen: Book Review: Out of His Mind – Bayo Adebowale". Thought with Pen. 2015-09-12. Retrieved 2020-01-17.
"Archived copy" (PDF). Archived from the original (PDF) on 2015-04-10. Retrieved 2015-04-04
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 2015-04-10.