Bayo Omoboriowo
Bayo Omoboriowo (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàlá oṣù karùn-ún ọdún 1978) jẹ́ ayawòrán-kọròyìn ọmọ bíbí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Òun ni ayàwòrán àgbà fún Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà lọ́wọ́́lọ́wọ́, Muhammadu Buhari.
Báyọ̀ Ọmọ́boríowó | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 13 Oṣù Kàrún 1987 |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Lagos |
Iṣẹ́ | Official photographer to President Muhammad Buhari |
Olólùfẹ́ | Lola Omitokun[1][2] |
Website | bayoomoboriowo.com |
Ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀
àtúnṣeỌmọ bíbí ìlú Èkó ni Báyọ̀ Ọmọ́boríowó. Kódà, Muṣin, ní ìlú Èkó lo tí dàgbà.[3] Báyọ̀ kàwé gboyè dìgírì nínú ìmọ̀ Applied Chemistry ní ifáfitì tí ìjọba àpapọ̀ tí ó wà ní ìpínlẹ̀ Èkó, University of Lagos.[4][5]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Inemesit, Udodiong. "Buhari's official photographer, Bayo Omoboriowo, tied the knot with his bride over the weekend.". Pulse ng. Archived from the original on 5 August 2015. https://web.archive.org/web/20150805025916/http://pulse.ng/weddings/bayo-omoboriowo-more-photos-from-buharis-official-photographers-wedding-id4037041.html. Retrieved 3 August 2015.
- ↑ Olajiga, Damilola. "Wedding Photos Of President Buhari’s Photographer, Bayo Omoboriowo". 360nobs. Archived from the original on 11 August 2015. https://web.archive.org/web/20150811222641/http://www.360nobs.com/2015/08/wedding-photos-of-president-buharis-photographer-bayo-omoboriowo/. Retrieved 1 August 2015.
- ↑ "Bio". Bayo Omoboriowo. Archived from the original on 2 October 2016. Retrieved 28 September 2016.
- ↑ Iwuchukwu, Chukwudi. "Bayo Omoboriowo: The Entrepreneur Who Became President Buhari’s Photographer". Entepre news. Archived from the original on 26 January 2017. https://web.archive.org/web/20170126015827/http://entrepre-news.com/bayo-omoboriowo-the-entrepreneur-who-became-president-buharis-photographer. Retrieved 10 June 2015.
- ↑ Awomodu, Gbenga. "Rising Photographer Bayo Omoboriowo talks to BN about His Passion for Documentary Photography and Nigeria". Bella Naija. https://www.bellanaija.com/2012/08/rising-photographer-bayo-omoboriowo-talks-to-bn-about-his-passion-for-documentary-photography-and-nigeria/. Retrieved 10 August 2012.