Ben Murray-Bruce

Olóṣèlú

Ben Murray-Bruce jẹ́ oníṣòwò,[1] olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Ìlà Oòrùn Balyesa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2011 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party. Ó jẹ́ olùdásílẹ̀ Silverbird Group.[2][3]

Ben Murray-Bruce
aṣojú Ìlà Oòrùn Balyesa ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà.
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
Oṣù Kàrún 29, 2015 (2015-05-29)
AsíwájúClever Ikisikpo
ConstituencyÌlà oòrùn Balyesa
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí17 Oṣù Kejì 1956 (1956-02-17) (ọmọ ọdún 68)
Ìlú Èkó
Ọmọorílẹ̀-èdèỌmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPDP
(Àwọn) olólùfẹ́Evelyn Murray-Bruce
EducationSt. Gregory's College, Lagos
Alma materUniversity of South Carolina
OccupationOlóṣèlú, àti onị́ṣòwò
Known forSilverbird Group
Websitebenbruce.org
benmurraybruce.com


Àwọn ẹ̀bùn àti ẹ̀yẹ

àtúnṣe
  • "Showbiz Icon of the Year Award" (2005)
  • "“Top Ten” Significant Nigerian Businessmen Award" (2006)
  • "Life Achiever Award" (2006)
  • "Champion for Nation Building Award" (2007)
  • "Excellent Personality Award" (2009)
  • "Officer of Order of the Niger|the Order of the Niger" (2014)[4]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Florence Amagiya (27 December 2014). "A peep into Ben Bruce business empire". Vanguard Nigeria. Retrieved 2015-06-17. 
  2. Richard Osunde (13 March 2013). "Ben Murray Bruce". Biography Home. Retrieved 2015-06-17. 
  3. Emmanuel Aziken, Political Editor, Samuel Oyadongha & Henry Umoru (14 November 2011). "Bayelsa Guber ticket: PDP finally drops Sylva, Alaibe, Bruce". Vanguard Nigeria. Retrieved 2015-06-17. 
  4. Richard Akinwumi (29 September 2014). "Jonathan names Nigeria’s national flag designer, Akinkunmi, special aide for life". Premium Times. Retrieved 2015-06-18.