Benedict Akwuegbu
Agbaọ́ọ̀lù ọmọ orílé-éde Nàìjíríà
Benedict Akwuegbu (tí a bí ní ọjọ́ kẹta oṣù kọkànlá ọdún 1974) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ẹlẹ́sẹ̀ ti tẹ́lẹ̀ tó fẹ̀hìntì.
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Benedict Akwuegbu | ||
Ọjọ́ ìbí | 3 Oṣù Kọkànlá 1974 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Jos, Nigeria | ||
Ìga | 1.80 m (5 ft 11 in) | ||
Playing position | Striker | ||
Youth career | |||
1989–1991 | Mighty Jets F.C. | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
1991–1992 | RC Lens | ||
1992–1993 | K.S.C. Eendracht Aalst | 15 | (3) |
1994–1996 | Harelbeke | 49 | (14) |
1996–1997 | Waregem | 16 | (9) |
1997–1998 | Tienen | 27 | (4) |
1998–2002 | Grazer AK | 100 | (31) |
2002 | → Shenyang Ginde (loan) | 18 | (2) |
2002–2004 | Grazer AK | 20 | (7) |
2004 | FC Kärnten | 14 | (6) |
2004–2005 | St. Gallen | 12 | (3) |
2005–2006 | Wacker Innsbruck | 11 | (0) |
2006 | Siegen | 10 | (1) |
2006 | → Tianjin Teda (loan) | 6 | (3) |
2006–2007 | Panserraikos | 10 | (12) |
2007 | Qingdao Jonoon | 20 | (6) |
2008 | Beijing Hongdeng | 7 | (2) |
2009–2010 | Basingstoke Town | 4 | (1) |
National team | |||
2000–2005 | Nigeria | 35 | (10) |
Teams managed | |||
2012–2013 | Heartland F.C. (Asst General Manager) | ||
2015–2016 | FC Gratkorn (Manager) | ||
2016– | Mighty Jets F.C. (Technical Director) | ||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Iṣẹ́ Agbábọ́ọ̀lù Rẹ̀
àtúnṣeEarly career
àtúnṣeAkwuegbu bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ agbábọ́ọ̀lù ẹlẹ́sẹ̀ rẹ̀ nígbà tí ó wà ní àárun-dín-lógún ọdún ní ọjọ́ orí ní Nàìjíríà kí ó tó lọ sí French outfit RC Lens nígbà tí ó wà ní ẹ̀ẹ́ta-dín-lógún ọdún ní ọjọ́ orí. [1] Lẹ́hìn náà, ó lo ọdún márùn-ún ní Belgium pẹ̀lú KRC Harelbeke, KSV Waregem, KVK Tienen. Ẹgbẹ́ Austrian Grazer AK ṣe ìtẹ́wọ́gbà rẹ̀ lẹ́hìn àsìkò odún 1998.
Ìyìn
àtúnṣe- Grazer AK
- Austrian Football Bundesliga: 2003–04; runner-up 2002–03
- Austrian Cup: 2000, 2002
- Austrian Supercup': 2000, 2002
- International
- Africa Cup of Nations: Runner-up: 2000
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "Benedict Akwuegbu". National-Football-Teams.com. Retrieved 17 June 2008.