Ife Ẹ̀yẹ àwọn Orílẹ̀-èdè Áfríkà
(Àtúnjúwe láti Africa Cup of Nations)
Ife Ẹ̀yẹ àwọn Orílẹ̀-èdè Áfríkà (Africa Cup of Nations tabi African Cup of Nations tabi African Nations Cup, lonibise bi CAN (Faranse fun Coupe d'Afrique des Nations), ni idije boolu-elese akariaye ni Afrika. O wa labe akoso Ijoparapo Boolu-elese Afrika (CAF), o si koko waye ni 1957. Lati 1968, o ti n waye leyin odoodun meji.
Ìdásílẹ̀ | 1957 |
---|---|
Agbègbè | Áfríkà (CAF) |
Iye ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù | 16 |
Aborí Lọ́wọ́ | Côte d'Ivoire (2nd title, 2015) |
Lọ́wọ́ | Ẹ́gíptì (7 titles, including one as UAR) |
Èsì
àtúnṣeÀkótán èsì
àtúnṣe- ^ South Africa were disqualified from the tournament due to the country's apartheid policies.
- ^ Only three teams participated.
- ^ There was no final match; the three teams played each other once, with the winner on points receiving the Cup. It finished: UAR 4pts, Sudan 2, Ethiopia 0.
- ^ There was no final match; the tournament was decided in a final group contested by the last four teams. It finished: Morocco 5pts, Guinea 4, Nigeria 3, Egypt 0.
- ^ The third-place match was tied 1–1 when the Tunisian team withdrew from the field in the 42nd minute in protest at the officiating. Nigeria were awarded a 2–0 walkover.
- ^ No extra time was played.
- Key:
- aet – after extra time
- penalties – after penalty shootout
Èsì gẹ́gẹ́bí orílẹ̀-èdè
àtúnṣeOrílẹ̀-èdè | Aborí | Ipò Kejì | Ipò Kẹta | Ipò Kẹrin | Top 4 |
---|---|---|---|---|---|
Ẹ́gíptì | 7 | 1 | 3 | 3 | 14 |
Ghánà | 4 | 5 | 1 | 3 | 13 |
Kamẹrúùn | 4 | 2 | 1 | 1 | 8 |
Nàìjíríà | 3 | 4 | 7 | - | 14 |
Côte d'Ivoire | 2 | 2 | 4 | 2 | 10 |
OO Kóngò | bgcolor=gold|2 | - | 2 | 1 | 5 |
Zambia | 1 | 2 | 3 | - | 6 |
Tùnísíà | 1 | 2 | 1 | 2 | 6 |
Sudan | bgcolor=gold|1 | 2 | 1 | - | 4 |
Àlgéríà | 1 | 1 | 2 | 2 | 6 |
Ethiópíà | 1 | 1 | 1 | 2 | 5 |
Mòrókò | 1 | 1 | 1 | 2 | 5 |
Gúúsù Áfríkà | 1 | 1 | 1 | - | 3 |
Kóngò | 1 | - | - | 1 | 2 |
Málì | - | 1 | 2 | 3 | 6 |
Sẹ̀nẹ̀gàl | - | 1 | - | 3 | 4 |
Ùgándà | - | 1 | - | 1 | 2 |
Bùrkínà Fasò | - | 1 | - | 1 | 2 |
Guinea | - | 1 | - | - | 1 |
Líbyà | - | 1 | - | - | 1 |
Guinea Alágedeméjì | - | - | - | 1 | 1 |
Total | 30 | 30 | 30 | 30 | 120 |
Aborí gẹ́gẹ́bí agbègbè
àtúnṣeÌparapọ̀ (Agbègbè) | Aborí | Iye |
---|---|---|
UNAF (North Africa) | Egypt (7), Algeria (1), Morocco (1), Tunisia (1) | 10 titles |
WAFU (West Africa) | Ghana (4), Nigeria (3), Cote d'Ivoire (2) | 9 titles |
UNIFFAC (Central Africa) | Cameroon (4), Congo DR (2), Congo (1) | 7 titles |
CECAFA (East Africa) | Ethiopia (1), Sudan (1) | 2 titles |
COSAFA (Southern Africa) | South Africa (1), Zambia (1) | 2 titles |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |