Bernardo Alberto Houssay (10 Oṣù Kẹrin 1887 – 21 Oṣù Kẹ̀sán 1971) je Argentine onimo oro-edainuara to gba idaji Ebun Nobel fun Iwosan ni 1947, fun iwari to se nipa ipa ti pituitary hormones unko ninu akoso iye suga eje (glukosi) ninu awon eranko. Ohun ni ara Argentina ati Latin Amerika akoko elebun Nobel laureate ninu awon sayensi. (O pin ebun na pelu Carl Ferdinand Cori ati Gerty Cori, ti won gba fun iwari ti won se nipa ipa ti glukose unko ninu isemetabolisti karboniolomi.)[1] je onimo sayensi .

Bernardo Houssay
Bernardo Houssay
Ìbí(1887-04-10)Oṣù Kẹrin 10, 1887
Buenos Aires, Argentina
AláìsíSeptember 21, 1971(1971-09-21) (ọmọ ọdún 84)
Buenos Aires, Argentina
Ọmọ orílẹ̀-èdèArgentine
PápáPhysiology, endocrinology
Ó gbajúmọ̀ fúnGlucose
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síNobel Prize for Physiology or Medicine (1947)