Beverly Afaglo

A bí Beverly Afaglo Baah ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kaàrún ọdún 1983. Ó jẹ́ òṣèré orílẹ̀ èdè Ghana àti olóòtú TV.

Beverly Afaglo
Ọjọ́ìbíBeverly Afaglo Baah
Ọjọ́ kẹjìdínlọ́gbọ̀n osù kàrún ọdún 1983
Orílẹ̀-èdèGhanaian
Ẹ̀kọ́Ghana Institute of Journalism
Iṣẹ́|Òsèré|Onímọ̀ nípa ẹwà ara}}
Olólùfẹ́Akọrin Eugene Kwadwo Boadu Baah]]
Àwọn ọmọỌmọbìrin Méjì

Ìgbésí ayéÀtúnṣe

Beverly wá láti Agbègbe Volta ní orílẹ̀ èdè Ghana. Ó ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú Eugene Kwadwo Boadu Baah pẹlu ìrújú díẹ̀ wọ́n sì ní àwọn ọmọbìrin méjì.

Iṣẹ́Àtúnṣe

Beverly kọ́ ẹ̀kọ́ gẹ́gẹ́bí onímọ̀ nípa bí a sé ń sàtúnse ẹwà ní FC Institute of Beauty Therapy, Ghana ó tún jẹ́ akéèkọ́ tẹ́lẹ̀ rí ní Ghana Institute of Journalism níbi tí ó ti kọ́ ẹ̀kọ́ nípa ìròyìn àti ọ̀rò tó ń lọ. Yàtọ̀ sí iṣẹ́ eré ṣíṣe, ó jẹ́ alákóso Glamour Beauty Salon ní Tema .

Eré oníṣe tí sà yànÀtúnṣe

Ààmì ẹ̀yẹ àti yíyànÀtúnṣe

Odun Ebun Ile-iṣẹ olugba Abajade Ref
Ọdun 2010 Oṣere ti o dara julọ ni Ipa Atilẹyin (Gẹẹsi) 2010 Ghana Movie Awards funrararẹ |style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé
Ọdun 2010 Ti o dara ju oṣere ni awada Awọn ẹbun Terracotta (Nigeria)|Gbàá

Àwọn ìtọ́kasíÀtúnṣe